Browsing Category
Uncategorized
E-Naira: Ààrẹ Buhari sèfilọ́lẹ̀ owó orí ẹ̀rọ ayélujára
Ààrẹ orìlẹ̀ èdè Nàíjíríà Muhammadu Buhari ti ṣe ifilọlẹ E-Naira, owo ẹrọ ayelujara.
Ayẹyẹ naa waye lọjọ Aje ni ile aarẹ to wa niluu Abuja.
Aarẹ sọrọ yii lasiko ti alakoso ile-ifowopamọ ti orilẹ ede Naijiria,(Central Bank of…
Ẹ dẹ́kun nípa bíba àwọn ọ̀pá epo jẹ́ – à̀arẹ Buhari
Aarẹ orilẹ ede Naijiria,Muhammadu Buhari ti rọ awọn oludari Ogoni to wa ni ẹkùn Niger-Delta lati tubọ maa rọ awọn eniyan lati maa daabobo awọn ohun ìnì bii ọ̀pá epo rọbi ati awọn ti wọn lo lati pọn epo rọbi ni orilẹ ede yii.…
Ayẹyẹ EndSARS : Àwọn ikọ̀ ọmọ ogun kò yìnbọn pa àwọn a-fẹ̀hònúhàn ní ibùdó ọkọ̀ Lekki –…
Ijọba orilẹ ede Naijiria ti tun tẹnumọ ọn pe , ikọ ọmọ ogun orile ede Naijiria ti wọn ko lọ lati pese aabo ni ipinlẹ Eko, paapaa julọ ni ibudo ọkọ Lekki ko yinbọn pa ẹnikankan ninu awọn to fẹhonuhan lati gbogun t bi awọn ọlọpaa SARS se n hu…
Ìdùnnú subú layọ̀! Ìtọ́jú ti wà fún àwọn tó nì àrùn jẹjẹrẹ
Oludari ile akede Naijiria,( Voice of Nigeria, VON), Osita Okechukwu ti sapejuwe ile -itọju arun jẹjẹrẹ ti wọn kọ si ipinlẹ Kano gẹgẹ bi eto iranwọ fun awọn to ba ni arun ọhun..
O tẹsiwaju pe ierti ti wa bayii fun itọju arun…
Ẹ̀yin ọ̀dọ́ , ẹ lọ́wọ́ sí òsèlú Naijiria
Igbakeji aarẹ orile ede Naijiria, ọjọgbon Yemi Osinbajo ti rọ awọn ọdọ orilẹ ede Naijiria ki wọn tubọ maa lọwọ ninu oselu orilẹ ede yii nitori pe gbogbo eniyan ni oselu wà fun.
Osinbajo sọrọ yii lọjọ Aje lasiko ayẹyẹ ìfì̀wé lọ́lẹ̀…
Amnesty International kò ní ẹ̀tọ́ lábẹ́ òfin láti wà lórílẹ̀-èdè Nàíjíríà –…
Ijọba orilẹ ede Naijria ti bu ẹnu atẹ lu ọrọ ti ẹgbẹ Amnesty International ( A-ja fẹtọ-ọmọniyan lagbaaye) sọ nipa orilẹ ede Naijiria ,ijọba sọ pe “Wón ti pinnu lati maa gbe lẹ́yìn awọn ọlọtẹlai bikita fun awọn eniyan ti awọn ọdaran yii…
Ẹ̀yin dókítà , a ò dún ìkookò mọ́ọ yín láti padà sẹ́nu isẹ́, sùgbọ́n ètò ò sisẹ́, kò…
Minisita fun eto ilera lorilẹ ede Naijiria, Osagie Ehanire ti ni ahesọ ọrọ ni pe ijọba n dun ìkookò mọ awọn ẹgbẹ awọn dokita to n se itọju abẹle to n yan isẹlodi lati pada sẹnu isẹ́ wọn.
Minista fun eto ilera lo sọrọ yii pẹlu awọn…
A ti mú àwọn oníṣòwò òògùn egbòogi olóró mẹ́tàlélógójì – NDLEA
Àjọ tó ń gbógun ti gbígbé àti mímu òògùn egboogi olóró lórílẹ̀ èdè Nàíjíríà,NDLEA ti mú àwọn oníṣòwò òògùn olóró mẹ́tàlélógójì ni ipinlẹ Nasarawa, Benue ati Ondo.
Olùdarí ẹka to n mojuto iroyin ni…
Ẹni tí Sango bá tojú rẹ jà,kò ní bá wọn bú ọba kòso,ẹni tí ogun Biafra bá sojú rẹ̀,kò…
Gomina ipinlẹ Kano, Abdullahi Umar Ganduje ti rọ gbogbo awọn to n kọrin pe ki orilẹ ede pín , kí wọ́n gba ìtùbí-ìnùbí laaye , nitori pe ti orilẹ ede Naijiria ba pin, ko ni ṣe ẹnikakan ni anfaani.
Gomina ipinlẹ Kano sọrọ yii…
Ààrẹ Buhari di adarí ẹgbẹ́ PAGGW
Ààrẹ Muhammadu Buhari kò ni pẹ́ di adari ẹgbẹ́ (PAGGW) ni oṣu kẹsan an, ọdun 2021.
PAN-GGW, jẹ ẹgbẹ́ tiwọn gbé kalẹ̀ lati mu iyipada rere bá àwọn ilẹ Afirika ati lati mu ipinnu wọn sẹ latí yí ìgbésí ayé miliọnu awọn eniyan…