ÌRÒYÌN YÀJÓ-YÀJÓ
- Sarkin Hausawa Ìlú Ìbàdàn Gbésẹ̀: Makinde Kẹ́dùn Pẹ̀lú Olúbàdàn Àti Ẹ̀yà Hausa Ní Ìlú Ìbàdàn
- Ẹgbẹ́ ikọ̀ Agbábóòlù Chelsea Yan Liam Rosenoir Gẹ́gẹ́ Bí Olukọni Àgbà Fún Ẹgbẹ́ Náà
- Ẹ jẹ́ kí Àlàáfíà Joba Lásìkò Ìdìbò Ọdún 2027: Gómìnà Ìpínlẹ̀ Akwa Ibom
- Ẹgbẹ́ Ọmọ Ológun Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà Tú Àṣírí Àwọn Oníṣẹ́ Láabi Ni Ìpínlẹ̀ Adamawa.
- Ẹgbẹ́ Ọmọ Ológun Orílẹ̀-èdè Ṣe Ìfilọ́lẹ̀ ìpàdé Fún Ìdanilẹ́ẹ̀kọ́ Odún 2026.
- Ètò ìṣúná owó Ọdún 2026 Jẹ́ Àtìlẹ́yìn Nlá Fún Ààrẹ Tinubu: Mínísítà Fún Ọ̀rọ̀ Tó Ńlọ
- Ikọ̀ Super Super Eagles Lu Ikọ̀ Mozambique Ní Àlùbami Pẹ̀lú Ayò Mẹ́rin Sí Òdo(4-0) Peregedé Sì Ipele Tó Súnmọ́ Àsekágbá Ìdíje AFCON.
- Ilé ẹjọ́ tó gajù lọ ní Guinea fìdí àṣeyege ìbò Ààrẹ Doumbouya muĺẹ̀
- Ecowas Pé Fún Ọwọ̀ Lórí Ìjọba Venezuela
- Manchester United Tí Lé Olùkọ́ni Wọ́n Ruben Amorin
ÌRÒYÌN ÀGBÁYÉ
Ecowas Pé Fún Ọwọ̀ Lórí Ìjọba Venezuela
Àwùjọ Ètò-ọrọ-àjé tí Àwọn Orílẹ̀-èdè Ìwọ̀-oòrùn Áfíríkà (ECOWAS) sọ pé àwọn wó idagbasoke túntún tí ń lọ́ ní…
Póòpù Leo Kẹrìnlá Kéde Láti Gba Àlàáfíà Láyè
Olórí Kátólíìkì, Póòpù Leo Kẹrìnlá, ti ké sí àwọn olórí l'àgbáyé, àwọn ìjọba àti àwọn aráàlú láti gba òun tó pè ní…
APEC Ṣé Ìkìlọ̀ Nípa Àwọn ipá Owó-orí-òwò Ọjọ́ Kẹ́ẹ́dógún Ní Oṣù Kàrún, Ọdún 2025
Ẹgbẹ́ Ìṣọ̀kan Ìṣòwò Asia àti Pacific (APEC) tí ṣé ìkìlọ̀ ní Ọjọ́bọ̀ pé àwọn ọjà òkèèrè ní àgbègbè náà kì yóò dàgbà…
Orílè-èdè Amẹ́ríkà Pẹ̀lú China Ṣetán Ìpàdé Àpapọ̀ Ní Geneva
Ọ̀gbẹ́ni Scott Bessent àti Jamieson Greer ti orílẹ̀-èdè Amerika yóò pàdé pọ̀ pẹ̀lú He Lifeng ti ilẹ̀…
ÌRÒYÌN ÀṢÀ ÀTI ÌṢE YORÙBÁ
Gómìnà Zulum Gbàlejò Ìpàdé Àsà Ti Kanem-Borno
Gomina ipínlẹ̀ Borno, Babagana Umara Zulum, ti gbàlejò ìpàdé ọ̀gọ̀rọ̀ ẹgbẹgbẹ̀run ẹ̀yà ènìyàn Kanuri ó kéré tán…
ÌRÒYÌN ORÍLẸ̀-ÈDÈ NÀÍJIRÍÀ
Sarkin Hausawa Ìlú Ìbàdàn Gbésẹ̀: Makinde Kẹ́dùn Pẹ̀lú Olúbàdàn Àti Ẹ̀yà Hausa Ní…
Gómìnà Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́, Seyi Makinde ti fi ikú Sarkin Hausawa ìlú Ìbàdàn, Alahji Ali Dahiru Zungeru we àdánù nla.…
ÌRÒYÌN ÁFÍRÍKÀ
Ikọ̀ Super Super Eagles Lu Ikọ̀ Mozambique Ní Àlùbami Pẹ̀lú Ayò Mẹ́rin Sí Òdo(4-0)…
Ikọ̀ Super Eagles borí ìdíje wọn ní papa isere Fes nígbà ti wọn lù alútakò wọn, Mozambique bí ẹní lu aṣọ…
ÌRÒYÌN ÒSÈLÚ
Ẹ jẹ́ kí Àlàáfíà Joba Lásìkò Ìdìbò Ọdún 2027: Gómìnà Ìpínlẹ̀ Akwa Ibom
Gómìnà ìpínlẹ̀ Akwa Ibom Olùṣọ Àgùntàn Uma Eno ti pe àwọn ará ìlú ati àwọn Olóṣèlú láti jẹ ki Àlàáfíà Joba Lásìkò Ìdìbò Odun 2027.
Gómìnà mu amoran àlàáfíà yìí wa lasiko ti wọn se idupe ọdun tuntun ni gbo gán International Worship ni…
Ààrẹ Tinubu Ṣèpàdé Pẹ̀lú Paul Kagame Ní Paris
Ààrẹ Bola Tinubu ti ṣé ìpàdé bóǹkẹ́lẹ́ pẹ̀lú Ààrẹ Orílẹ̀-èdè Rwanda, Paul Kagame, ní Paris, France, níbi tí àwọn olórí méjèèjì ti jíròrò àwọn ọrọ àgbáyé àti tí Áfíríkà.
Ìpàdé bóǹkẹ́lẹ́ náà jẹ́ ìgbà àkọ́kọ́ ti Ààrẹ Tinubu tí yóò…
Peter Obi darapọ̀ mọ́ ADC fún ìdìbò ọdún 2027
Olùdíje fún ipò Ààre ti ẹgbẹ́ Labour ní ọdún 2023, Ọ̀gbẹ́ni Peter Obi, ti darapọ̀ mọ́ ẹgbẹ́ African Democratic Congress (ADC), ẹgbẹ́ òṣèlú ìṣọ̀kan, fún ìdìbò gbogbogbòò 2027.
Obi kede ifi ẹgbẹ rẹ silẹ ni Ọjọọru, ọjọ…
Gómìnà Nwifuru Gbóríyìn Fún Àwọn Àṣeyọrí Ni Orísirísi Ọnà Ni Ìpínlẹ̀ Ebony.
Gómìnà Francis Nwifuru ti gbóríyìn fún àwọn àṣeyọrí àti àwọn ìdàgbàsókè to sẹlẹ̀ ni ìpínlẹ̀ Ebony nipa ètò Ẹ̀kọ́ àti ìlera.
Nwifuru so èyí di mímọ̀ lásìkò to n ṣe idupẹ nile ìjósìn láti sààmì sí ayẹyẹ ọdun ìjọba awaarawa ni Abakaliki.…
ÌRÒYÌN ÌDÁNILÁRAYÁ
Gómìnà Zulum Gbàlejò Ìpàdé Àsà Ti Kanem-Borno
Gomina ipínlẹ̀ Borno, Babagana Umara Zulum, ti gbàlejò ìpàdé ọ̀gọ̀rọ̀ ẹgbẹgbẹ̀run ẹ̀yà ènìyàn Kanuri ó kéré tán…
ÌRÒYÌN ÌLERA
Ẹgbẹ́ ran àwọn tó ye ààrun jẹjerẹ ọyàn bọ́ lọ́wọ́ ni Anambra
Ẹgbẹ́ àwọn obìnrin ìpínlẹ̀ Anambra, ní Amẹ́ríkà Inc. àti Ẹgbẹ́ obìnrin ìpìnlẹ̀ Anambra ti Amẹ́ríkà tí…
Ìpínlè Anambra: Ṣẹ́nítọ̀ Bí Ẹnu Àtẹ Lu Bí Wọn Ṣe Ti Ọjà Onitsha Pa Fún Ìgbà Pípẹ́.
Dọ́kítà Tony Nwoye to jẹ Ṣẹ́nítọ̀ to n sojú ìpínlẹ̀ Anambra ti bu ẹnu àtẹ lù bí wọn ṣe tí ọjà Ogbo Ogwu ti wa ni…