Take a fresh look at your lifestyle.
Browsing Category

ÌRÒYÌN ÒSÈLÚ

This is a category for politics news

Aiyedatiwa Jáwé Olúborí Gẹ́gẹ́ Bí Olùdíje Sí Ipò Gómìnà Níbí Ìdìbò Abẹ́lé Ẹgbẹ́…

Gómìnà Lucky Aiyedatiwa ti ìpínlẹ̀ Ondo ni wọ́n ti kéde gẹ́gẹ́ bí ẹni tí ó jáwé olúborí níbi ìdìbò abẹ́lé ẹgbẹ́ òsèlú APC láti yan olùdíje lábẹ́ àsìá ẹgbẹ́ náà fún ìdìbò sí ipò gómìnà tí yóò wáyé…

Ààbò Tí Ó Péye Yóò Wà Lásìkò Ìdìbò Ìjọba Ìbílẹ̀ Ní Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́- Àjọ…

Àjọ Ọlọ́pàá Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ ti fún àwọn olùgbé Ìpínlẹ̀ ní àrídájú láti má se fòyà àtipé ìdáàbòbò tí ó péye yóò wà fún ẹ̀mí àti dúkìá àwọn ará ìlú gẹ́gẹ́ bí àkókò ìdìbò ìjọba ìbílẹ̀ se ń…

Adarí Ilé Ìgbìmọ̀ Asòfin Ìpínlẹ̀ Anambra Pè Fún Ìfẹ́ Lásìkò Àti Lẹ́yìn Àjí-ìn-de

Adarí Ilé Ìgbìmọ̀ Asòfin Ìpínlẹ̀ Anambra, Ọ̀gbẹ́ni Somtochukwu Udeze ti rọ ọmọ Nàìjíríà papàá jùlọ àwọn ọmọ lẹ́yìn kírísítì láti tẹ̀lé ìlànà, ẹ̀kọ́, ìfẹ́, ìfarajì, àlàáfíà  èyí́ tí ikú àti àjídìde…