
Browsing Category
ÌRÒYÌN ÈTÒ Ọ̀GBÌN
Ààrẹ Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà Yóò Lọ Ṣí Ìlú Dakar Fún Ìpàdé Lórí Ètò Ọ̀gbin
Ààrẹ Muhammadu Buhari yóò kúrò ní ìlú Èkó lọ sí Orílẹ̀-èdè Sẹ́nẹ́gà ní ọjọ́ Ìṣẹ́gun fún ìpàdé elẹ́kejì irú rẹ̀ ti àgbáyé lórí ètò ọ̀gbìn.
Ààrẹ Macky Sall ti ilẹ̀ Sẹ́nẹ́gà tó tún jẹ́ alága àgbáríjọpọ̀ Ilẹ̀ Adúláwọ̀ ni…
Olùdarí Àjọ FABDA Pè Fún Àtúnṣe Ẹ̀ka Ètò Ọ̀gbìn
Olùdarí àjọ Fisheries and Aquaculture Business Development Agency (FABDA), Emeka Illoghalu, ti Ìpínlè Anambra ti pè fún àtúnṣe ẹ̀ka ètò ọ̀gbìn ní gbogbo ìpínlẹ̀ àti ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà lápapọ̀ ní wàrànsesà. Eléyìí yóò mú kí…
Ìjọba Nàìjíríà Gbèrò Láti Fẹ́ Àwọn Òpópó-ònà Ìgbèríko Àtí Ìṣẹ́ Àgbẹ̀ Ní Gbogbo Ìpínlẹ̀ Orílẹ̀-èdè…
Ìjọba Nàìjíríà sọ pé òun ń gbèrò látí fẹ́ òpópó-ònà ìgbèríko àti ìtàjà iṣẹ́ àgbẹ̀ (Rural Access and Agricultural Marketing Projects RAAMP), ní gbogbo ìpínlẹ̀ mẹ́rìndínlógójì tí àjọ náà.
Alàkóso ìṣẹ́ àkànṣe náà tí Orílẹ̀-èdè yìí…
Ìjọba Nàìjíríà Se Àgbékalẹ̀ Ìgbìmọ̀ Tí Yóò Sàgbéyẹ̀wò Ìpalára Ìyípadà Ojú Ọjọ́
Ìjọba Àpapọ̀ ti ṣe àgbékalẹ̀ ìgbìmọ̀ láti se àmúsẹ àfẹnukò lórí ìpalára tí ìyípadà ojú ọjọ́ ń fà ní àwùjọ wa. Èyí tí ó wáyé ní ìlú Nguru, ìpínlẹ̀ Yobe, orílẹ̀ èdè Nàìjíríà.
…
Ìpínlẹ̀ Edo Ṣe Ìrànlọ́wọ́ Fún Àwọn Àgbẹ̀ Ọlọ́sìn Adìẹ
Ìjọba ìpínlẹ̀ Edo, pẹ̀lú ìfọwọ́sowọ́pọ̀ àwọn ilé iṣẹ́ ọlọ́sìn Adìẹ yóò se ìrànlọ́wọ́ fún àwọn àgbẹ̀ ẹgbẹ̀rún lọ́nà ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ̀ta (500,000).
Ó fi ọ̀rọ̀ náà léde níbi àpéjọ kan ní Ikpoba, ìjọba…
Ìjọba Pín Ohun Èlò Ọ̀gbìn Fún Àwọn Tí Ó Lùgbàdì Omíyalé
Ìjọba ìpínlẹ̀ Ondo ti bẹ̀rẹ̀ láti máa pín ohun èlò ọ̀gbìn fún àwọn tí omíyalé dà láàmú lójúnà àti ṣe ìgúnpá fún wọn àti fún ìtẹ̀síwájú ètò ọ̀gbìn.
Gómìnà ìpínlẹ̀ náà, Rotimi Akeredolu…
Emir Gbóríyìn Fún Ìjọba Ìpínlẹ̀ Gombe Lórí Ọ̀gbìn Alikama
Emir ìlú Nafada, ìpínlẹ̀ Gombe, Alhaji Muhammadu Hamza ti lu ìjọba ìpínlẹ̀ náà lọ́gọ ẹnu fún síse ìgúnpá fún àwọn àgbẹ̀ tí ó ń gbin alikama (wheat) ní ìpínlẹ̀ náà.
Ó fi ọ̀rọ̀ náà léde ní ààfin…
Gbajúgbajà Ọdẹbìnrin Rí Àgbéga Lórí Ètò Ààbò
Akin obìnrin tí ó jẹ́ ọdẹ, Aisha Bakari ti rí ìyànsípò gẹ́gẹ́ bíi adarí àwọn ọdẹ tí ó gbógun ti ìgbésùmọ̀mí àti ìgbénipa, (Directorate of Hunting and Forestry of the Nigerian Hunter and Forest Security Services, NHFSS).…
Oúnjẹ yóò wà lọ́pọ̀ janturu ní 2023 – ilé-iṣẹ́
Ilé-iṣẹ́ ìjọba àpapọ̀ tó ń rísí ètò Ìdàgbàsókè ilẹ̀ ọ̀gbìn (NALDA),ti ṣàlàyé pé, kò ní sí àìtó oúnjẹ ní orílẹ̀-èdè, tí ó sì tún ń fi dá àwọn ọmọ Nàìjíríà lójú pé eebi kò ní pa wọ́n ní ọdún…