Take a fresh look at your lifestyle.
Browsing Category

ÌRÒYÌN ORÍLẸ̀-ÈDÈ NÀÍJIRÍÀ

This is a Nigeria news category

Ẹ̀yin dókítà, ẹ fagilé ìyansẹ́lódì yín, kí ẹ sì padà sẹ́nu isẹ́ ní kíákíá- Adajọ…

Ilé- ẹjọ́ tó ń gbọ́ awuye-wuye lórí ọrọ to ba jẹ mọ awọn osisẹ ati ijọba ((Nigeria Industrial court) to n gbẹjọ gbọ́nmi-si -omi-ò- to waye laarin ijọba apapọ  ati egbe  awon dokita lorile ede Naijiria(Resident Doctors) ti pàsẹ pe ki…

Ìgbìmọ̀ aláṣẹ àpapọ̀ FEC fọwọ́sí iye owó tótó bílíọ̀nù méjìdín-lógójì Náírà…

Ìgbìmọ̀ aláṣẹ àpapọ̀ ti fọwọ́sí iye owó tótó bílíọ̀nù méjìdín-lógójì fún píparí àwọn  iṣẹ́ àkànṣe òpópónà ní ìpínlẹ̀ márùn – ún jákàjádò orílẹ̀-èdè. Minisita fun Iṣẹ ati Ibugbe, Babatunde Fashola…

Igbákejì ààrẹ,Ọ̀jọ̀gbọ́n Ọ̀sínbàjò polongo ìtẹ̀sìwájú lórí Ìṣòwò iṣẹ́ àkànṣe…

Igbákejì ààrẹ orílẹ̀ -èdè Nàìjíríà, Ọ̀jọ̀gbọ́n Yẹmí Ọ̀sínbàjò sọ pé àwọn akitiyan ti ó ń lọ lọ́wọ́lọ́wọ́ láti fi òpin sí ìdàgbàsókè àwọn iṣẹ́ àkànṣe gáásì ní ilẹ̀ adúláwọ̀ lòdì sí àwọn ìpilẹ̀…