Take a fresh look at your lifestyle.
Election

Ọmọ Ẹgbẹ́ Òṣèlú APC, Umar Namadi Jáwé Olúborí Nínú Ìbò Gómìnà Ìpínlẹ̀ Jigawa

Àjọ INEC ti kéde ọmọ ẹgbẹ́ All Progressives Congress (APC), Umar Namadi gẹ́gẹ́ bí ẹni tí ó jawe olúborí nínú Ìbò Gómìnà tó wáyé ní ọjọ́ kejìdínlógún ní Ìpínlẹ̀ Jigawa . Olùkéde ìbò fún ìpínlẹ̀ náà, ọ̀jọ̀gbọ́n Zayyanu Umar Birnin Kebbi ló…

Ọmọ Ẹgbẹ́ Òṣèlú APC, Ahmad Aliyu Jáwé olúborí Nínú Ibo Gómìnà Ìpínlẹ̀ Sokoto

Àjọ INEC ti kéde ọmọ ẹgbẹ́ APC, Ahmad Aliyu gẹ́gẹ́ bí ẹni tí ó yege nínú Ìbò Gómìnà ti Ìpínlẹ̀ Sokoto Olùkéde ìbò fún Ìpínlẹ̀ náà, Ọ̀jọ̀gbọ́n Armiya’u Hamisu sọ pé ọ̀gbẹ́ni Aliyu borí pẹ̀lú ìbò 45,3661. Ẹni tó se ipò Kejì wá láti inú…

Olúbàdàn Ilẹ Ìbàdàn Kí Gómìnà Makinde Kú Oríire Ìyànsípò Rẹ̀ Gẹ́gẹ́ Bíi Gómìnà Fún Sáà Kejì

Olubadan Ilẹ Ìbàdàn kí Gómìnà Seyi Makinde kú oríire fún bí o ṣe jáwé olubori nínú ètò ìdìbò Gómìnà tó kọjá, nígbà tí o lù Ajọ Eleto Ìdìbò INEC ni Ìpínlè náà l'ogo ẹnu fún àṣeyọrí ètò ìdìbò tí ọdún yìí. Olúbàdàn Ilẹ Ìbàdàn, Oba Lekan…

Ọ̀rọ̀ Àkọ́sọ Seyì Makinde Gẹ́gẹ́ Bíi Gómìnà Fún Sáà Kejì Ní Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́

Lẹyin tí Àjọ Eleto Ìdìbò INEC ní Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ kéde Gómìnà Seyì Makide gẹgẹ bíi ẹni tí o jáwé olubori nínú ètò ìdìbò gómìnà to wáyé ní Àbámẹ́ta ọjọ Kejidinlogun oṣù yìí, Makinde fi ìdùnnú rẹ̀ hàn sí àṣeyọrí náà nígbà tí o n ba àwọn oníròyìn…