Browsing Category
ÌRÒYÌN ÌDÁRAYÀ
This is a category for sport news
Brighton Se Ikọ̀ Man U Sìbá-Sìbo Pẹ̀lú Àmì Ayò 4-0
Àìsàn tó ń yọ ikọ̀ agbábọ́ọ̀lù Manchester United lẹ́nu kò ì tíì san rárá pẹ̀lú bí ikọ̀ Brighton & Holve Albion se nà wọ́n bí ẹní na asọ òkè. Àmì ayò mẹ́rin sí òdo ní wọ́n kó lé wọn lọ́wọ́.
Ipo kẹfa ni wọn…
Ikọ̀ Liverpool Àti Ikọ̀ Real Madrid Yóò ti Ẹsẹ̀ Bọ Sòkòtò Kan Fún Ifẹ Ìdíje UEFA…
Látàrí bí ikọ̀ Real Madrid se móríbọ́ nínú ìfẹsẹ̀wọnsẹ̀ tí wọ́n ní pẹ̀lú ikọ̀ Machester City pẹ̀lú àmì ayọ̀ 6-5; áwọn pẹ̀lú ikọ̀ Liverpool ni yoo jọ waaya ija, ti wọn yoo si fi ẹsẹ bọ inu sokoto kan ni ilu Paris, Orilẹ ede…
Ọ̀gá àgbà fún ètò Ààbò ti CAF yóò dupò ààrẹ NFF
Olórí ètò ààbò,àkójọpọ̀ agbábọ́ọ́lù àfẹsẹ̀gbá adúláwọ̀,CAF, Dokita Christian Emeruwa ti kéde èróńgbà rẹ̀ láti díje fún ipò ààrẹ ẹgbẹ́ agbábọ́ọ́lù Nàìjíríà.
Alakoso agba awọn agbabọọlu afẹsẹgba lọwọlọwọ…
Ẹgbẹ́ agbábọ̀ọ̀lù Arsenal fi idi Ẹgbẹ́ agbábọ̀ọ̀lù West Ham Janlẹ̀ ní ọjọ́ ìsinmi
Ẹgbẹ́ agbábọ̀ọ̀lù Arsenal gba aaye kẹrin lori Premier League lẹhin ti wọn dánáyá ẹgbẹ́ agbábọ̀ọ̀lù West Ham pẹ̀lúu àmi ayò méjì sí ọ̀kan. Rob Holding àti Gabriel Magalhaes ló mi àwọ̀n fún ẹgbẹ́ agbábọ̀ọ̀lù Arsenal ní…
Ẹgbé Agbábọ̀ọ̀lù Real Madrid jáwé olúborí nínú ìdíje La liga ti ọdún 2022
Ẹgbé agbábọ̀ọ̀lù Real Madrid jáwé olúborí nínú ìdíje La liga nígbà tí wọ́n fi ẹgbé agbábọ̀ọ̀lù Espanyo ṣe eré ọwọ́ lóríi pápá pẹ̀lúu àmi àyò mẹ́rin sódo
Ẹgbé agbábọ̀ọ̀lù Madrid ò kúkú ní lò láti mi…
WAFCON 2022: Ẹgbẹ́ Agbábọ̀ọ̀lù Orílẹ́-ẹ̀dè Nàìjíríà yóò kojú Ẹgbẹ́ Agbábọ̀ọ̀lù South…
Ẹgbẹ́ Agbábọ̀ọ̀lù àgbà àwọn obìnrin Orílẹ́-ẹ̀dè Nàìjíríà, Super Falcons, yóò kojú South Africa, Burundi ati Botswana ní Group C ti ìdíje àwọn obìnrin Áfíríkà ti 2022 ni Ilu Morocco.
Mohamed VI Complex ní ìjọba…
Agbábọ́ọ́lù Orílẹ̀-èdè Egypt, Mohamed Salah gba àmì ẹ̀yẹ FWA Ọdún yìí
Ẹgbẹ́ òǹkọ̀wé bọ́ọ́lù àfẹsẹ̀gbá ti fún Agbábọ́ọ́lù àgbáyé, ọmọ orílẹ̀-èdè Egypt tí ó tún jẹ́ agbábọ́ọ́lù fún Liverpool, Mohamed Salah ti gba àmì ẹ̀yẹ ọkùnrin agbábọ́ọ́lù ọdún níbi ìdìbò ọdọọdún ti…
CAF sún ìdíje eré bọ́ọ̀lù Ìfẹsẹ̀wọnsẹ̀ síwájú
Àjọ Bọ́ọ̀lù Ilẹ̀ Áfíríkà, CAF ti kéde pé wọ́n ti sún ìdíje eré bọ́ọ̀lù Ìfẹsẹ̀wọnsẹ̀ nílẹ̀ Áfíríkà (CHAN) ní ọdún 2023 síwájú
CAF kéde ìfilọ̀ yìí ní ojú òpó twitter rẹẹ̀
CHAN draw postponed https://t.co/tzipq3y1kM
— CAF…
Àparò Chelsea Kò Ga Ju Manchester United; Man U 1- 1 Chelsea
Ninu ifẹsẹwọnsẹ ọjọ ọjọbọ ti idijẹ English Premier League laarin ikọ Manchester United at ikọ Chelsea; aparo kan ko ga ju ọkan lọ, latari bi awọn ikọ mejeeji sẹ ta ọmi.
Gbogbo ipa lati ri ẹyin awọn lo pin fun Chelsea, bo tilẹ jẹ pe…
Ìjọba Nàìjíríà pinnu Láti Tún pápá ìṣerẹ́ Sùrúùlérè ṣe
Mínísítà fún ọ̀dọ́ àti ìdàgbàsókè eré ìdárayá, Sunday Dáre, ti tún tẹnumọ pé ìjọba àpapọ̀ ṣetán láti tún pápá ìṣèré orílẹ̀-èdè tí ó wà ní Sùrúùlér̀e ní ìlú Èkó ṣe gẹ́gẹ́ bí ó ti se ti Moshood…