Take a fresh look at your lifestyle.
Browsing Category

Ìròyìn Ẹ̀kọ́

Ìmọ̀ Àtọwọ́dá (AI) Lè Rọ́pò Oníròyìn Tó Bá Kọ̀ Láti Ní Ìmọ̀ Ẹ̀rọ Díjítà Òde Òní – Alága Ẹgbẹ́…

Alága àgbáríjọ ẹgbẹ́ oníròyìn ní Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́, NUJ, Akeem Babatunde Abas ti sọ di mímọ̀ pé ọgbọ́n àtọwọ́dá ti a mọ̀ sí Artificial Intelligence (AI) lè rọ́pò àwọn oníròyìn tí ò bá kọ̀ láti kọ́ ẹ̀kọ́ nípa ìmọ̀ díjítà ode òní. Abas ló sísọ…

Nàìjíríà Tún Ṣé Ìdánilójú Ìdúróṣinṣin Sí Ètò Ẹ̀kọ́ Àwọn Ọmọ-kékeré ‎

‎Ìjọba Nàìjíríà tí tún ṣé ìdánilójú ìdúróṣinṣin fún ìtọ́jú ẹ̀kọ́ àti ìdàgbàsókè àwọn ọmọ-kékeré (ECCDE) lágbára gẹ́gẹ́ bí ẹ̀kọ́ ìpìlẹ̀ tó dára àti ìdàgbàsókè orílẹ̀-èdè. ‎ ‎ Mínísítà fún ẹ̀kọ́, Dókítà Tunji Alausa sọ èyí nínú ọ̀rọ̀ ìkíni…

Nàìjíríà Fìdí Ìfaramọ́ Rẹ̀ Múlẹ̀ Fún Ètò Ẹ̀kọ́ Ọ̀dọ́mọbìnrin ‎

Mínísítà fún Ìpínlẹ̀ fún ètò Ẹ̀kọ́, Ọ̀jọ̀gbọ́n Suwaiba Ahmad, tí tún ṣé ìdánilójú ìfaramọ́ tí ìjọba Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà látí fí àgbàrá fún àwọn ọ̀dọ́mọbìnrin Nàìjíríà nípasẹ ìsopọ̀, ifọkanbalẹ àti ètò ẹ̀kọ́ tó dídára. ‎ ‎ O ṣé ìdánilójú yìí…
button