Take a fresh look at your lifestyle.
Browsing Category

ÌRÒYÌN ILẸ̀ ÀFÍRÍKÀ

This is a category for Africa news

ìjà ogun TIGRAY: Adarí ìgbìmọ̀ ìjọba orílẹ̀ èdè Ethiopia bẹ̀bẹ̀ fún ìrànwọ́ àwọn ará…

Adarí ìgbìmọ̀ ìjọba orílẹ̀ èdè Ethiopia Abiy Ahmed  ti rawọ ẹ̀bè si  gbogbo àwọn  ọmọ orílẹ̀-èdè Ethiopia láti darapọ̀ mọ́  ikọ̀ àwọn ọmọ ogun  orilẹ ede naa láti kọjú ogun ti ikọ̀ àwọn ọlọ̀tè ní àwọn agbègbè ẹkùn …

ORÍLẸ̀-ÈDÈ AMẸRIKA YÓÒ sèrànwọ́ fún ORÍLẸ̀-ÈDÈ SUDAN láti ní ìdàgbàsókè lori…

Orílẹ̀-èdè Amẹrika ti sọ pé àwọn yóò fọwọ́sowọ́pọ̀ pẹ̀lú orílẹ̀-èdè Sudan láìmọye ọ̀nà lóri bí wọ́n yóò se mú ìdàgbàsókè bá ètò ọrọ̀ ajé wọn àti àwọn ohun mííràn tí  yóò mú ìdàgbàsókè bá àwọn…

Àwọn ènìyàn mókànlélógún tí wọn sá kúrò lòrìlẹ-èdè wọn ló kú sínú omi ní…

Àwọn ènìyàn mókànlélógún ni wọn rí tí wọn ti kú léyìn gbàtí ọkọ ojú omi subú sínú omi Tunisia. Olùsọ  ojú omi kan sọpé ẹkejì tí irú ìyí yóò selẹ láàrin ọjọ méjì nìyí. Àwọn tí wọn n sọ ojú omi sí…