Take a fresh look at your lifestyle.
Browsing Category

ÌRÒYÌN ILẸ̀ ÀFÍRÍKÀ

This is a category for Africa news

Bísọ́ọ̀bù Àgbà Orílẹ̀-èdè South Africa Tọrọ Àforíjì Látàrí Ẹ̀sùn Ìlòkulò Ọmọdé

Bísọ́ọ̀bù àgbà ti ìlú Cape Town se ìpàdé ní ọjọ́ ìṣẹ́gun lẹ́yìn àgbéyẹ̀wò tí wọ́n rí pé àwọn ìgbìmọ̀ mọ̀ pé ìjọ Anglican ni South Africa kùnà láti sọ fún àwọn ìjọ míràn ewu tó lágbára tó wà níbẹ látàrí ìlòkulò ọmọdé lọ́wọ́…

Àwọn alájọṣepọ̀ ààrẹ Benin fi ẹ̀wọ̀n ogún ọdún gbára lórí ìgbèrò ìfipá gbàjọba

Àwọn arákùnrin méjì kan tí wọ́n súnmọ́ ààrẹ orílẹ̀ - èdè Benin, ti fi ẹ̀wọ̀n ogún ọdún gbára lẹ́yìn ìgbà tí wọ́n mú wọn lọ́dún tó kọjá lórí ìgbèrò ìfipá gbàjọba lórílẹ̀ èdè náà. Ile Ẹjọ ti n risi ẹṣẹ…

Ẹgbẹ́ Òsèlú Democratic Alliance Gbé Pẹ́rẹ́gi Ìjà Kaná Pẹ̀lú Ìjọba Orílẹ̀-èdè South…

Ẹgbẹ́ òsèlú DA ti fi ojú ìjà hàn sí ìjọba tí ó wà lóde látàrí bí ìjọba se kùnà láti kó àkóyawọ́ èyí tí yóò fún gbogbo ẹgbẹ́ òsèlú láyè láti dásí ètò ìsèjọba, papàájùlọ nípa ètò ìlera àti…
button