Ààrẹ Tinubu Yìn Àjọ IFC Fún Owó Ìdókòwò Àádọ́ta Mílíọ̀nù Dọ́là
Ààrẹ Bola Ahmed Tinubu tí gbóríyìn fún àjọ tó ń rí sí ètò ìnáwó àgbáyé (IFC) fún owó ìdókòwò àádọ́ta mílíọ̀nù dọ́là ní àgbègbè Ọ̀fẹ́ ní Èkó.
Iyìn yìí wá latari ìgbàgbọ́ tí àjọ náà ní nínú ètò ọrọ àjé Nàìjíríà, Ààrẹ Tinubu nínú ọrọ…