Take a fresh look at your lifestyle.

Nàìjíríà Gbóríyìn fún Ìgbìmọ̀ Kan Lórí Ìdìbò Ìgbìmọ̀ IMO

Ìjọba Nàìjíríà ti fi àwọn lẹ́tà ìyìn ránṣẹ́ sí àwọn ọmọ ẹgbẹ́ mẹ́sàn-án kan ti Ìgbìmọ̀ Àjọṣepọ̀ láti mọrírì àwọn iṣẹ́ wọn tó tayọ̀ nínú àṣeyọrí ìdìbò Nàìjíríà sí Ẹ̀ka C ti Ìgbìmọ̀ Òṣìṣẹ́ Orí-Omí Àgbáyé tí (International Maritime…

Igbákejì Ààrẹ Shettima Fẹ́ Ìlọsíwájú Ọrọ̀-Ajé Fún Àǹfààní Àwọn Aráàlú ‎

Igbákejì Ààrẹ Kashim Shettima ti rọ àwọn Gómìnà ìpínlẹ̀ mẹ́rìndínlógójì ní Nàìjíríà, àwọn Mínísítà àti àwọn òṣìṣẹ́ ìjọba mìíràn láti ṣiṣẹ́ láti ṣàṣeyọrí irú ìdàgbàsókè àti ìlọsíwájú ọrọ̀-ajé tó ń tàn kálẹ̀ sí ìgbésí ayé ojoojúmọ́ àwọn ọmọ…

Ìjọba Nàìjíríà ti bẹ̀rẹ̀ sí ní ṣe àwọn òun pàtàkì nínú àdéhùn tí wọ́n tún ṣe pẹ̀lú Ẹgbẹ́ Àwọn Ọ̀gá Ilé-ẹ̀kọ́ gíga (ASUU). ‎ ‎ ‎ Mínísítà fún Ẹ̀kọ́, Dókítà Maruf Tunji Alausa, nínú ìkéde tí Olùdarí Ìròyìn, Boriowo Folashade, gbé jáde, sọ…

‎Ganduje Gbóríyìn Fún Mínísítà FCT Lori Àgbékalẹ̀ Ìrànwọ́ Gíga Fún Àwọn Aráàlú Kano

Ìyàwó Gómìnà tí Ìpínlẹ̀ Kano tẹ́lẹ̀ ríi, Ọ̀jọ̀gbọ́n Hafsat Abdullahi Ganduje, tí gbóríyìn fún Mínísítà fún Ìpínlẹ̀ Agbègbè Olú-ìlú Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà (FCT), Dókítà Mariya Mahmoud, fún ìfilọ́lẹ̀ òun tó pè ní ètò agbára tó gbòòrò ati tó…

Àwọn Olùwakùsà Yanrìn Ń Wá Kí Ìjọba Tán Ìmọ́lẹ̀ Sí Òfin Lórí Odò ‘Niger’

Àwọn Òṣìṣẹ́ ní ẹ̀ka iwakùsà yanrìn odò ní Nàìjíríà ti rọ Àjọ 'National Inland Waterways Authority (NIWA)' láti ṣé ìtọ́sọ́nà lórí òfin àti ìlànà lórí odò Niger, wọ́n ṣàfihàn òfin onígbá méjì ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ láti ọ̀dọ̀ Ìjọba àpapọ̀ àti tí ìpínlẹ̀…
button