Take a fresh look at your lifestyle.
Browsing Category

ÌRÒYÌN ÌDÓKOÒWÒ

This is a category for business news

Aáwọ̀ okòwò: Ààrẹ Bùhárí rán Àwọn Aṣójú Sí orílẹ̀-èdè Ghánà

Ààrẹ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, Mùhámmádù Bùhárí ti  ṣọ  pé kí  aṣojú kán lọ sí orílẹ̀-èdè Ghánà láti yanjú aáwọ̀ ọlọ́jọ́ pípẹ́  tó ti wà  láàrin àwọn oníṣòwò Nàìjíríà àti ìjọba orílẹ̀-èdè Ghánà.…

Ẹ̀yin agbódegbà àti fàyàwọ́,ẹ tọwọ́ ọmọ yín bọsọ, kẹ́ máa jẹyán yín níṣu-Adamu

Ilé isẹ́ asọ́bodè orílẹ̀ èdè Nàíjíríà ti ẹkùn Ọyọ/Ọsun ti kéde  pé òhun ti pa owó tó lé díẹ̀ ni Bilioni Márùndínlógún (N15,890,479.26) ní àlàfo ọjọ́ kínni osù kejì sí ọgbọ̀njọ́ osù kerin ọdún tí a wà nínú…

Ẹ jẹ́ àwòkọ́se láti fún àwọn òsìsẹ́ ilé- ẹjọ́ àti asòfin ní òmìnira ní ìpínlẹ̀…

Alága ẹgbẹ́ àwọn òsìsẹ́ onísòwò ní  ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ (TUC), Comrade Emmanuel Ogundiran ti rawọ́ ẹ̀bẹ̀ si gomina ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́, Seyi Makinde láti gbé ìgbésẹ̀ nípa síse àmúlò òmìnira àwọn  òsìsẹ́  asòfin àti…