Browsing Category
Ìròyìn Àyíká
Àbàwọ́n Epo: Ìpínlẹ̀ Bayelsa Kọ Ìròyìn Sí Ààrẹ
Gómìnà ìpínlẹ̀ Bayelsa, Douye Diri ti bẹbẹ fún àtìlẹyìn ààrẹ Bola Tinubu fún àmúlò iroyin ọ̀nà abayọ sí wàhálà ti àbàwọ́n epo n fà sí àyíká àti ìpínlè náà lápapọ̀.
Gómìnà jẹ́ ko di mímọ̀ nǹkan ti àwọn ará ìlú ń là kọja nípa…
Akpabio Rọ Àjọṣepọ̀ Ètò Ààbò Tó Le Daindain Bí Ọba Se Se Òkú Ìyàwó Rẹ̀
Ààrẹ gbogbo àwọn Senetọ̀, Godswill Akpabio ti pé gbogbo àwọn Gómìnà gúsù ila oòrùn (Ipinle Anambra, Enugu, Imo, Abia, Ebonyi) àti àwọn olùgbé ìpínlẹ̀ náà lati se ara wọn lọ́kan ni ọ̀nà láti so ètò ààbò le dain-dain.
Ìpè yìí…
Mínísítà Nipa Iṣẹ́ Ọnà Ṣèlérí Àjọṣepọ̀ Pẹ̀lú Mínísítà Àná, Ade-John Fún Ìgbéga Ètò Ìrìnàjò Àti…
Mínísítà iṣẹ́ ọnà, àṣà àti ìrìnrìnàjò àti ọgbọ́n àtinúdá ọ̀rọ̀ aje, Hannatu Musawa ti sọ pé òún yóò gba ìmòràn ati iriri ẹni iṣaju òun, Lola Ade-John lò fún ìtèsíwájú ẹ̀ka náà.
Níbi ayẹyẹ ìfisẹ́léniilọ́wọ́ ni Ọ́fíìsì rẹ̀ ni…
Ìpínlẹ̀ Katsina: Igbákejì Ààrẹ Shettima Yóò Ṣì Ètò Lesẹ́wọ̀gbẹ́, Ìrónilágbára
Awon ọdọ ipinle Katsina ti n dunnu sile fún dide Igbakeji Ààrẹ Kashim Shettima sí ìpínlẹ̀ náà ní ojó Àbámẹ́ta.
Igbakeji Aare ni igbagbọ wa pe yóò ṣe iside ètò ironilagbara ti amúgbá-lẹ̀gbẹ́ agba sí ààrẹ lori ọ̀rọ̀ oṣelu, Alhaji…
Oúnjẹ yanturu: Asọ́bodè Nàìjíríà Dá Ọ̀pọ̀ Ọkọ̀ Tó Ń Kó Oúnjẹ Lọ Ìlú Ibòmíràn Dúró
Ní ọ̀nà lati jẹ ki ounje sùnwábọ̀ ni orile-ede yii, àjọ awọn Asọ́bodè ti kéde pé àwọn ti da ọkọ̀ nla ti oye rẹ jẹ ọgọfa duro lọ́nà to n ko ounjẹ orisirisii lọ sí gbogbo agbegbe orílẹ̀-èdè Naijiria.
Olórí àwọn Asọ́bodè Nàìjíríà, ọgbẹni…
Ọjọ́ Àyájọ́ Àwọn Obìnrin Lágbáyé: Mínísítà Gbóríyìn Fún Àwọn Obìnrin
Mínísítà orile-ede Naijiria ni eka ti aṣa, ẹwà ọnà ati ọgbọn atinuda ọrọ ajé, Hannatu Musawa ti ki awon obinrin ni ẹka náà ku oriire ayajọ awọn obinrin lagbaye.
Musawa fi ìdùnnú àti ìkíni rẹ ransẹ sí gbogbo àwọn obìnrin olorire…
Ilé iṣé Ìjọba Ti Ó Ń Mójú Ìdọ̀tí Yóò Gba Ìbáwí: Ijoba Ìpínlẹ̀ Kwara.
Ìjọba Ìpínlẹ̀ Kwara ti ṣe ìkìlọ nla fún àwọn ilé iṣé to n mójú tó ìdọ̀tí lati ṣe iṣẹ wọn bí iṣẹ
Mínísítà fún ọ̀rọ̀ agbègbè Malam Shehu Ndanusa ló ṣe ìkìlọ náà lákòkóò to n bá wọn se ìpàdé ní ìlú Ilorin.
Ó ní isé wọn ní lati rí wí pé…
FCTA fa ibùsọ̀ ọkọ̀ Area 1 lé ẹgbẹ́ lọ́wọ́
Ibùsọ̀ ọkọ̀ ìlúmọ̀ọ́ká ti Area 1, ní Garki, Olú ìlú Nàìjíríà, Abuja ti fa ìṣàkóso àti ìṣiṣẹ́ ibùsọ̀ ọkọ̀ lé ẹgbẹ́ onímọ́tò lọ́wọ́.
Adari iṣẹ, ti iṣakoso ise lilọ bibibọ oju ọna, DRTS, Deborah Osho, sọ eleyi lasiko…
Àtúnṣe Gbogbo Ọ̀nà Ló Jẹ́wa Lógún – David Umahi
Mínísítà fún àkànṣe iṣẹ orílẹ̀-èdè yìí, David Umahi ti sọ pé àtúnṣe gbogbo ọ̀nà jakejado ilẹ̀ yi ló jẹ àwọn lógún.
" Gbogbo nǹkan ni ọ̀nà jẹ́, tí ẹ bá tú ọ̀nà se, ètò ààbò, ọ̀gbìn, ẹ̀kọ́, ọrọ̀ ajé àti ayọ̀ àwọn ènìyàn ni ẹ ti tún…
Ìjọba Ìpínlẹ̀ Èkó Se Kóríyá Fún Àjọ Akólẹ̀-kódọ̀tí
Gómìnà Ìpínlẹ̀ Èkó, Babajide Sanwo-Olu ti buwọ́lu àlékún owó tí ó jẹ́ ti ìparí ọdún fún àjọ akólẹ̀-kódọ̀tí ti ìpínlẹ̀ Èkó, LAWMA.
Alákòóso Àjọ LAWMA, Ọ̀mọ̀wé Muyiwa Gbadegẹsin sísọ lójú ọ̀rọ̀…