Take a fresh look at your lifestyle.
Browsing Category

ÌRÒYÌN ÀṢÀ ÀTI ÌṢE YORÙBÁ

This is a category for culture and life news

Mi ò ní yí padà kúrò lórí ìlànà bí wọ́n ṣe ń jẹ olúbàdàn -Ṣèyí Mákindé

Gómìnà ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́, Ṣèyí Mákindé ṣe àbẹ̀wò ẹkú araá-fẹ́ra kù sí opó Ọba Sálíù Adétúnjí, Ajéogungun I, Olúbádàn ti ìlú Ìbàdàn tí ó sì fi àsìkò ọ̀hún sèlérí pé ìjọba ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ yóò ṣe ayẹyẹ…

Gbogbo pápá ìseré ẹlẹ́kùnjẹkùn tó wà jákè- jádò ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ ni yóò gba àtúnse…

Gomina ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́,Seyi Makinde ti ní gbogbo pápá ìseré ẹlẹ́kùnjẹkùn tó wà jákè- jádò ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ ni yóò gba àtúnse to mọnyan lórí. Seyi Makinde sọrọ yii  lasiko ti wọn n síde papa isere Lekan Salami to wa ni…

Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ní dandan jẹ́mánì gbọ́dọ̀ dá gbogbo àwọn nkàn ìṣẹ̀ǹbáyé tí…

Ìjọba Nàìjíríà ti bèèrè fún ìdápadà gbogbo àwọn  ojì-din-lẹwá le ni ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ́fà Idẹ  ti ilu Benin tí wọ́n  gbẹ́sẹ̀ lé  ní orílẹ̀-èdè Áfíríkà ní ọdún 19th, tí wọ́n sì sọ ibùgbé rẹ̀ di   ilé-ìṣọ́ Jẹ́mánì.…

Ètò Oúnjẹ lọ́pọ̀ yanturu yóò gbọn òṣì dànù-igbákejì Òsíǹbàjò

Igbákejì ààrẹ, orilẹ ede Naijria, Ọ̀jọ̀gbọ́n Ọ̀síńbàjò sọ pé,ìgbìyànjú orílè-èdè láti pèsè oúnjẹ lọ́pọ̀ yanturu jẹ́ ọ̀kan pàtàkì lára ilànà láti dẹ́rù bòṣì jákèjádò  orilẹ ede Nàìjíríà. Ọjọgbọn…