Take a fresh look at your lifestyle.
Browsing Category

ÌRÒYÌN ÀṢÀ ÀTI ÌṢE YORÙBÁ

This is a category for culture and life news

Aṣáájú Nàìjíríà Gbá Àkọlé Àṣà Ìbílẹ̀ Tó Gíga Jùlọ Ní Akwa Ibom ‎

Ìgbìmọ̀ Àwọn Alàkóso ìbílẹ̀ tí Ìpínlẹ̀ Akwa Ibom tí ṣé ọla fún Ààrẹ Bola Ahmed Tinubu pẹ̀lú àkọlé tó gá jùlọ tí "Otuekong," èyí tó ṣàfihàn Ààrẹ gẹ́gẹ́bí Alàkóso àgbà ní Ìpínlẹ̀ Akwa Ibom. ‎ ‎ Ibù-ọlá fún Ààrẹ náà ló wáyé ní ọjọ́ Ẹtì ní…

Mínísítà Nipa Iṣẹ́ Ọnà Ṣèlérí Àjọṣepọ̀ Pẹ̀lú Mínísítà Àná, Ade-John Fún Ìgbéga Ètò Ìrìnàjò Àti…

Mínísítà iṣẹ́ ọnà, àṣà àti ìrìnrìnàjò àti ọgbọ́n àtinúdá ọ̀rọ̀ aje, Hannatu Musawa ti sọ pé òún yóò gba ìmòràn ati iriri ẹni iṣaju òun, Lola Ade-John lò fún ìtèsíwájú ẹ̀ka náà. Níbi ayẹyẹ ìfisẹ́léniilọ́wọ́ ni Ọ́fíìsì rẹ̀ ni Abuja,…

Ààrẹ Tinúbú Gbóríyìn Fún Ọọ̀ni Ilé Ifẹ̀ Fún Gbígbé Àṣà Àti Ìse Ilẹ̀ Yorùbá Lárugẹ

Ààrẹ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, Bọ́lá Ahmed Tinubú ti gbósùbà ràbàndẹ̀ fún Ọọ̀ni ti ilé-ifẹ̀ (Oba Adeyeye Ogunwusi) látàrí bí ó se ń gbé àṣà àti ìṣe ilẹ̀ Yorùbá lárugẹ. Ààrẹ Tinubu wí pé, láti ìgbà Kábíyèsí ti gorí ìtẹ́ baba rẹ̀, ìṣàkóso rẹ̀…
button