Ìperegedé Ìdíje AFCON: Agbábọ́ọ̀lù Simon, Ndidi, Àti Iheanacho Yóò Dé Sí Ìpàgọ́.
Agbábọ́ọ̀lù Nàìjíríà ní igun lórí pápá, Moses Simon pẹ̀lú Wilfred Ndidi àti Kelechi Iheanacho tí wọn ń gbá böọ̀lù fún ikọ̀ Leicester City yóò tètè dé sí ibùdó ìgbáradì Super Eagle ní Abuja látàrí ìfẹsẹ̀wọnsẹ̀ láàrín wọn àti ikọ̀ ti Guinea…