Mínísítà Àṣà Kí Àlàáfín Tuntun Ti Ìlú Ọ̀yọ́ Kú Oríire
Mínísita orílè-èdè yìí fún àṣà, iṣẹ, Ìrìn-àjò òun igbafe àti ọgbọ́n àtinúdá ọrọ̀ ajé, Hannatu Musawa ti kí Àlàáfín tuntun ti Ìlú Ọ̀yọ́, Ọba Abimbola Akeem Owoade, kú oríire, ti ìgorí ìtẹ́ baba rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí Aláàfin…