Take a fresh look at your lifestyle.

Gómìnà Fáyẹmí Yóò Sí Àwọn Ọ̀nà Titun Ní Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́

Gómìnà Ìpínlẹ̀ Èkìtì, Káyọ̀dé Fáyẹmí yóò sí àkànse àwon ọ̀nà tuntun ní ọjọ́ ọjọ́bọ̀ ní Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ Kọmísọ́nà fún ìròyìn, àsà àti ìgbafẹ́, Dókítà Wàsíù Ọlátúbọ̀sún ló sọ èyí ní…

Ikọ̀ Ọmọ Ogun Sọ Agbára Àwọn Agbésùòmí Di Òtu Bántẹ́ Ní Ọ̀nà Kàdúná Sí Záríà

Ikọ̀ ọmọ ogun àpapọ orílẹ̀ èdè yìí ti sọ agbára àwọn agbésùmọ̀mí méjì ní ọ̀nà Kàdúná sí Záríà ní ìjọba ìbílẹ̀ Igabi  ti ìpínlẹ̀ Kàdúná di òtu bántẹ́. Eléyìí jẹyọ nínú atejade ti wọ́n…

Òsìsẹ́ Ọlọ́pàá Ọ̀tẹlẹmúyẹ́ DSS Ti Nàìjíríà Fi Adúnàádúrà Àwọn Ajínigbé Sí…

Àwọn òsìsẹ́ Ọlọ́pàá DSS ti Nàìjíríà ti jẹ́ kó di mímọ̀  pé Adúnàádúrà àwọn ajínigbé Ọkọ̀ Reluwé tó ń lọ sí Kàdúná tí wọ́n fi ènìyàn sínú ìgbèkùn, Ọ̀gbẹ́ni Tukur Mamu sì wà ní àkàtà wọn.…