Ètò Ìdàgbàsókè Àwọn Ọ̀dọ́ Ní Niger Delta Ti Ààrẹ Tinubu Gba Àtìlẹ́yìn
Àwọn ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà láti agbègbè Niger Delta ni a ti sọ fún wọn láti kópa nínú àwọn ìlànà Ààrẹ Bola Tinubu tí ó da lórí àwọn ọ̀dọ́ láti mú kí ìdàgbàsókè yára síi.
Olóyè Mike Ebi Ayapaye, Olùdarí Àgbà àjọ Creek to Creek…