Take a fresh look at your lifestyle.

Orile-ede Botswana Ṣe Àtúnyẹ̀wò Àgbêkalẹ̀ Ìdámọ̀ràn Ìlera Àpapọ̀ Orílẹ̀-èdè Wọn

Botswana ti gbé ìgbésẹ̀ pàtàkì sí ààbò ìlera gbogbogbò lẹ́yìn tí àwọn alenulọ́rọ̀ pàtàkì ṣe àtúnyẹ̀wò àwọn ìdámọ̀ràn fún ètò Ìdámọ̀ràn Ìlera Orílẹ̀-èdè wọn tí a ṣe láti rí i dájú pé gbogbo ọmọ Motswana ní àǹfààní sí ìtọ́jú ìlera…

Ikọ̀ Senegal Kéde Àwọn Agbábọ́ọ̀lù Fún Ikọ̀ Orílẹ̀-èdè Peru, Gambia Nínú Idije Ọlọ́rẹ̀ẹ́sọ̀rẹ́

Senegal ti bẹ̀rẹ̀ sí ní múra sílẹ̀ fún ìdíje Ife Eye agbaye Ôdún 2026 pẹ̀lú Idije Ọlọ́rẹ̀ẹ́sọ̀rẹ́ pẹ̀lú orile-ede Peru àti àwọn aládùúgbò won, Gambia, wọ́n sì dúró pẹ̀lú ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ògbóǹtarigí agbaboolu tó díje ní ìdíje…

Igbákejì Ààrẹ Shettima kéde Fintiri Gẹ́gẹ́ Bí Aṣáájú Ẹgbẹ́ Òṣèlú APC Ní Ìpínlẹ̀ Adamawa

Igbákejì Ààrẹ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, Kashim Shettima, ti kéde Gómìnà Ahmadu Fintiri ti ìpínlẹ̀ Adamawa gẹ́gẹ́ bí aṣíwájú ẹgbẹ́ òṣèlú All Progressives Congress (APC) ní ìpínlẹ̀ náà. Ìkéde náà wáyé ní ọjọ́ Ajé níbi ayẹyẹ ńlá kan tí wọ́n ṣe…
button