Take a fresh look at your lifestyle.
Browsing Category

ÌRÒYÌN ÀGBÁYÉ

This is a category for world news

A kò rà mọ́

Orílẹ̀-èdè Taiwan ti sọ  ní ọjọ́bọ̀ pé òun kò rà àwọn bàálù kékeré  ìjagun abẹ́lẹ̀-omi láti Amẹ́ríkà mọ́,wípé ó ti wọ́n jù. Taiwan ti sọ tẹlẹ pe o n gbero lati ra awọn ọkọ ofurufu abelẹ-omi 12 MH-60R, ti Lockheed…

EU gbẹ́sẹ̀lé Epo orílè-èdè Rọ́síà Àti Àwọn ilé-iṣẹ́ agbóhùnsáfẹ́fẹ́ Mẹ́ta

Àjọ ìṣọ̀kan yúróópù EU yóò gbẹ́sẹ̀lé gbígbéwọlé epo orílẹ̀-èdè Rọ́ssíà, àwọn ọjà tí wọ́n túnṣe àti àwọn olùgbóhùnsáfẹ́fẹ́ ti ìjọba orílẹ̀-èdè Rọ́síà mẹ́ta gẹ́gẹ́ bí apákan ìdíi ìjẹniníyà kẹfà lórí…

Àwọn afẹ̀hónúhàn Sri Lanka Bèèrè Ìdájọ́ Fún ìkọlù Ọjọ́ àjíǹde Krísítì Ọdún 2019

Àwọn ọmọ orílẹ̀-èdè Sri Lanka ń fi ẹ̀hónúhàn láti bíi  ọjọ́ díẹ̀ sẹ́yìn nítósí ọ́fíísì ààrẹ tí wọ́n sí ǹ bèèrè fún ìdájọ́ òdodo fún àwọn olùfaragbà ìkọlù aburú Ọjọ́ àjíǹde Kírísítì tí ó   …

Shanghai pinnu láti fìyà jẹ ẹnikẹ́ni tó bá tàpá sófin ìgbélé ààrùn còrónà

Olú-ìlú ìṣòwò orílè-èdè Ṣáínà ní Shanghai  ti kìlọ̀ pé ẹnikẹ́ni tí ó bá rú àwọn òfin ìgbélé ààrùn còrónà  yóò jẹyán ẹ̀ níṣu. Ẹka ọlọpa ilu ṣalaye awọn ihamọ ti pupọ ninu awọn olugbe mẹedọgbọn miliọnu  …