Take a fresh look at your lifestyle.
Browsing Category

ÌRÒYÌN ÀGBÁYÉ

This is a category for world news

Omiyalé gbẹ̀mí ènìyàn mẹ́wàá Ní Ìlú Ítálì,tí wọ́n sì ń wá ọ̀pọ̀lọpọ̀

Òjò àrọ̀ọ̀dá kan ti ṣẹlẹ̀ tí ó si fa omiyalé àgbàrá ya ṣọ́ọ́bù ní agbègbè òkè-ńlá ní ààrin-ilà-oòrùn Ítálì,èyí tí ó gbẹ̀mí  ènìyàn mẹ́wàá , tí wọ́n sì ń wá ọ̀pọ̀lọpọ̀ báyìí, gẹ́gẹ́ bí rédíò…

EU Ṣé Ìfilọ́lẹ̀ Ètò Láti Ṣé àtìlẹ́yìn fún Ìjọba Awaarawa Ní Nàìjíríà

Àjọ Euroopu (EU) tí ṣé ìfilọ́lẹ̀ ètò kàn látí jẹ́ kí àwọn ará ìlú ní ìgbàgbọ́ àti igbẹkẹle nínú ètò ìdìbòyàn ati Ìjọba Awaarawa ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Gẹgẹ bí àjọ náà ṣé sọ, wọ́n yóò ṣé ìfilọ́lẹ̀ ètò náà ní Ọjọ́ Ajé, Ọjọ Kejìlá, Oṣù…