Ènìyàn kan péré ni Ọlọrun gbà Emi re là nínú ìjàmbá ọkọ̀ ojú omi ti o sẹlẹ̀, ti àwọn àdọ́ọ́ta sí pàdánù èmí wọn lásìkò ti ọkọ̀ ojú omi ríi.
Ọkùnrin kàn to jẹ Òṣìṣẹ́ orí omí ni oun ti wa nínú omi fún wákàtí merinlelogun gbáko ti òun sí rọ wí pè gbogbo àwọn to wa nínú ọkọ̀ ojú náà ti kú ṣugbọn ìyàlẹ́nu nla ni wí pè Ọlọrun gbà Emi enikan ka.
Ọkọ̀ ojú omi náà ni o gbera láti Orílè-èdè Tunisia ṣùgbón ko lẹ dè ibi ti o nlọ Látàrí ìjàmbá.
Ará Ọkùnrin kan ṣoṣo náà ti Ọlọrun ko yo náà ni àwọn òṣìṣẹ́ ojú omi Tunisia ti gbé ló sí Malta fún itọju to péye.