Browsing Category
KÓKÓ INÚ ÌRÒYÌN
This is a category for featured story
Ìdùnnú ṣubú layọ̀ àwọn ọmọ ẹgbẹ́ agbábọ́ọ́lù Flying Eagles
Ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù Nàìjíríà ti ́ kò ju ogún ọdún lọ Flying Eagles, ti pegedé Fún ìdíje ife ẹ̀yẹ adúláwọ̀ 2023,pẹ̀lú àmì ayò méjì sí ọ̀kan fún orílẹ̀-èdè Ivory Coast, fún ìdí èyí, ó ti kójú òsùnwọ̀n fún…
ASUP:Ilé-èkọ́ gíga iṣẹ́ ọwọ́ Násáráwá Darapọ̀ mọ́ ìyanṣẹlódì gbogbogbòò
Ẹgbẹ́ òṣìṣẹ́ olùkọ́ni ilé-ẹ̀kọ́ gíga iṣẹ́-ọwọ (ASUP), Isa Mustapha Agwai, Láfíà, ìpínlẹ̀ Násáráwá, Nàìjíríà ti darapọ̀ mọ́ ìkìlọ̀ ìdaṣẹ́sílẹ̀ ọlọ́sẹ̀ méjì tí ẹgbẹ́ náà kéde jákèjádò orílẹ̀-èdè lórí…
Gómìnà Ìpínlẹ̀ Èkó Pè fún ìrọ̀wọ́ rọsẹ̀ ìdìbò alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ egbẹ́ APC
Gómìnà ìpínlẹ̀ Èkó, Ọ̀gbẹ́ni Babajídé Sanwò-Olú, àti Ìgbìmọ̀ olùgbàmọ̀ràn ìjọba,GAC, ti ké sí àwọn aṣaájú àti àwọn ọmọ ẹgbẹ́ All Progressive Congress láti ṣe jẹ́jẹ́ lásìkò àwọn ìdìbò alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ àti…
NMA banújẹ́ Lórí Ètò Ìtọ́jú Ìlera Alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ tó mẹ́hẹ
Ẹgbẹ́ Ìṣòògùn Nàìjíríà (NMA),ti banújẹ́ lórí Ètò Ìtọ́jú Ìlera Alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ tó mẹ́hẹ ní Nàìjíríà,ó sọ pé ó léwu fún ìlera ọmọnìyàn.
Aarẹ ẹgbẹ naa, Dokita Innocent Ujah, sọ ni Port Harcourt, Ipinlẹ…
Gómìnà ìpínlẹ̀ Kano tẹ́lẹ̀ rí, Shekaráú, Fi APC sílẹ̀, Ó Darapọ̀ mọ́ NNPP
Gómìnà Ìpínlẹ̀ Kano tẹ́lẹ̀ rí, Sẹ́nétọ̀ Ibrahim Shekarau, ti fi ẹgbẹ́ òṣèlú All Progressives Congress, APC sílẹ̀,tí ó sì dara pọ̀ mọ́ ẹgbẹ́ òṣèlú New Nigeria Peoples Party, NNPP.
Oludari Agba fun ẹgbẹ to n ṣatilẹyin fun Asiwaju Bọla…
Minamino Mi Ikọ̀ Southampton Tì Tì
Bákan náà lọmọ́ sorí fún ikọ̀ Southampton. Ìyà tó gbóná ni ikọ̀ Liverpool fi jẹ wọ́n níwájú àwọn olólùfẹ́ wọn pẹ̀lú àmì ayò 2-1.
Bo tilẹ jẹ pe awọm ogbongẹ atamatase ikọ Liverpool bi Sadio Mane, Mohammed Salah ati…
Ikọ̀ Newcastle United Kọ Ojú Arsenal Sí Òrùn Ọ̀sán Gangan; Ìdíje UEFA Champions League Bọ́…
Gbogbo akitiyan Arsenal lati kopa ninu idije "UEFA Champions League" fun saa ti o n bọ ti ja si pabo latari bi ikọ Newcastle United se da erupẹ si gaari wọn.
Ami ayo meji si odo (2-0) ni wọn ko le wọn lọwọ. Saka, atamatase Arsenal ti fi…
Big Brother Nàìjá ẹlẹ́ẹ̀keje bẹ̀rẹ̀ ní pẹrẹu
Big Brother Nàìjá ẹlẹ́ẹ̀keje bẹ̀rẹ̀ ní pẹrẹu.
Awọn oluṣeto idije naa,fihan ninu fidio gigun iṣẹju kan ti o pin lori awọn ibaraẹnisọrọ lori ayelujara rẹ,o kede pe iṣafihan ọfẹ yoo nilo, ki awọn olukopa ṣafihan fidio iṣẹju mẹta lori…
Gómìnà Tambuwal dín ìséde oní Wákàtí mẹ́rìnlé-lógún kù Ní Ìpínlẹ̀ Sókótó
Ní Àtẹ̀lé ìfitónilétí kan nípasẹ̀ Àwọn olórí Ààbò ní Ìpínlẹ̀ Sókóto,́ Gómìnà Àmínù Wàzírì Tambuwal, ti pàṣẹ láti dín ìséde oní wákàtí -lógún ọ̀hún kù ní Ìpínlẹ̀ náà.
Ilana isede ti wọn tun…
Àwọn iṣẹ́ àkànṣe:Ẹ dá ṣẹ̀ríà fún àwọn olùgbaṣẹ́ṣe tí kò dúró déédé
Ìgbìmọ̀ tó ń mójútó owó ìfúnni ní àwọn ilé-ẹ̀kọ́ gíga (TETFund) ní Nàìjíríà, sọ pé ó ti fún àwọn ilé-ẹ̀kọ́ gíga tí ó ń jàǹfàní láti inú àwọn ìṣedúró rẹ̀ láṣẹ láti fòpin sí iṣẹ́ náà àti àwọn…