Àjọ Nigerian Institute of Public Relations (NIPR) ti gbe oye gíga fún gomina ipinle Nasarawa Abdullahi Sule latari imoriri idari rẹ, oju Iwoye àti ìdàgbàsókè to lagbara to Mu dè bá ipinle rẹ.
Ayẹyẹ náà wáyé ní ìlú Abuja, Ṣe àpèjúwe ipinlẹ̀ Nasarawa gẹgẹ bí ibí pataki agbaye fún Ibasepọ̀ ẹda àti ilé ìwe Fásitì àwọn àwọn Adarí.

Nigbati Gómìnà n dahun sì àwọn àpọ́nlé yìí, O dupẹ lọwọ wọn fún ìdánimọ̀ rẹ àti ìpínlè náà àti pé o tun soro lórí gbogbo nǹkan tó jẹ kí o seese fún ìlọsíwájú ìpínlẹ̀ náà.
Àwọn to wá síbi ayẹyẹ náà láti ri ọ̀gá agba ilé iṣẹ Voice of Nigeria, Malam Jibrin Baba-Ndace; igbákejì ààrẹ NIPR, Ọjọ̀gbọ́n Emmanuel Dandaura; ati Emir ti Keffi, Dokita Chindo Yamusa III.
Temitọ́pè Òbísẹ̀san