Take a fresh look at your lifestyle.
Browsing Category

ÌRÒYÌN YÀJÓ-YÀJÓ

This is a category for TRENDING NOW

Ààrẹ Tinubu ṣèdárò ikú mínísítà fún àwọn òṣìṣẹ́ tẹ́lẹ̀ rí, ọmọ ọba Alarape

 Ààrẹ Bọla Ahmed Tinubu ti ṣèdárò pẹ̀lú ẹbí mínísítà fún àwọn òṣìṣẹ́ tẹ́lẹ̀ rí,  Ọmọ Ọba Ajibọla Alarape Afonja, tí ó di olóògbé ní ọmọ ọdún méjì-lé-lọ́gọ́rin. Aarẹ ninu ifiranṣe idaro ti agbẹnusọ rẹ, Ajuri…

Àyájọ́ Ẹ̀jẹ̀ ríru Àgbáyé: Ìjọba Anambra ṣe àgbékalẹ̀ àyẹ̀wò ọ̀fẹ́

Ìjọba Anambra nípasẹ̀ Ilé Iṣẹ́ ìjọba àpapọ̀ tí ń mójútó ètò ìlera, ti ṣe àgbékalẹ̀ àyẹ̀wò ọ̀fẹ́ ní àwọn ilé ìwòsàn alákọ́bẹ̀rẹ̀ àti àwọn ilé ìwòsàn gbogbogbòò tìjọba jákèjádò ìpínlẹ̀, láti ṣàmì…

Mínísítà fún ètò ìbáraẹnisọrọ̀ pinnu láti ṣàtìlẹyìn fún EFCC bí ó ṣe ìfilọ́lẹ̀ Ẹ̀rọ…

Mínísítà fún ètò ìbáraẹnisọrọ̀ àti Ìṣàlàyé, Mohammed Idris ti sọ pé ó ṣe pàtàkì fún Ìgbìmọ̀ tí ń gbógunti Ẹ̀sùn Ọrọ̀ Ajé àti Ìnáwó (EFCC), láti ràròjinlẹ̀ àti lo ọgbọ́n nípa bí wọn yóo ̀ṣe máa fi…

Ààrẹ Tinubu ṣèdárò pẹ̀lú Gómìnà Sanwolu lórí ikú olùrànlọ́wọ́ rẹ̀

Ààrẹ Bọla Ahmed Tinubu ti ṣèdárò pẹ̀lú ẹbí igbákejì ọ̀gá àgbà fún àwọn òṣìṣẹ́ Gómìnà Babajide Sanwo-Olu, ti ìlú Eko, Ọ̀gbẹ́ni Gboyega Soyannwo. Nini ifiranṣe idaro ti agbẹnusọ aarẹ, Ajuri Ngelale, buwọlu aarẹ Tinubu…