Take a fresh look at your lifestyle.
Browsing Category

ÌRÒYÌN ÈTÒ Ọ̀GÌN ÀTI ÀYÍKÁ

Ẹ Kópa Nínú Ètò Ọ̀gbìn Lójúnà Àti Tán Ìsòro Ọ̀wọ́ngógó Oúnjẹ- Akọ́ṣẹ́mọṣẹ́

Àrọwà ti wá fún àwọn tí ó wà ní ìlú ńlá láti kópa nínú ètò ọ̀gbìn kí oúnjẹ le è pọ̀ lọ́pọ̀ yanturu, yóò sì tún mú kí ìsòro ọ̀wọ́ngógó oúnjẹ di àfìsẹ́yìn tí egúngún ń fi aṣọ. Àrọwà…

A Ti Setán Láti Mú Ìgbéga Bá Àgbẹ̀ Alábomirin Ní Ilẹ̀ Adúláwọ̀- Àjọ Tí Ọ̀rọ̀ Kàn

Àjọ tí ó wà fún ètò Àgbẹ̀-Alábomirin ti Yunifásitì Bayero, Kano ti pinnu láti kojú àwọn ìpèníjà tí ó n kojú ètò ọ̀gbìn Àgbẹ̀-Alábomirin ní ilẹ̀ Adúláwọ̀ gẹ́gẹ́ bí ó se ń kó ìpalára bá ìpèsè oúnjẹ ní…

Àwọn Tí Ìdágìrì Lé Kúrò Ní Ibùgbé Wọn Gba Ìdánilẹ́kọ̀ọ́ Lórí Lílo Ẹ̀Rọ Ìgbàlódé…

Kò dín ní àádọta ènìyàn nínú àwọn tí ìdágìrì lé kúrò ní ibùgbé wọn ni ó ti kọ́ ìmọ̀ ìgbàlódé nípa lílo àwọn ẹ̀rọ fún ètò ọ̀gbìn lójúnà àti pèsè iṣẹ́ àti oúnjẹ lọ́pọ̀ yanturu Àjọ kan…

Ẹ Fọwọ́sowọ́pọ̀ Láti Jẹ Ànfààní Ìjọba: Akọ́ṣẹ́mọsẹ́ kan Pàrọwà Sí Àwọn Alápatà

Alámòjútóó àgbà fún àwọn ọ̀rọ̀ ohun ọ̀sìn ní Ìpínlẹ̀ Plateau, Dokita Sipak Shse’et ti pàrọwà sí àwọn alápatà ní ìpínlẹ̀ náà láti gbé ìgbé àlàáfíà ní ibùdó ìpa ẹran, lójúnà àti jẹ ànfààní ìjọba.…