
Browsing Category
ÌRÒYÌN ÌDÁNILÁRAYÁ
This is a category for entertainment news
Don Crucifix Fakọyọ Jùlọ Gẹ́gẹ́ Bíi Olùkópa Nínú Eré
Olùkópa nínú eré kan tí à ń pe orúkọ rẹ̀ ní Tùmínínú Olúyọ̀lé ti gbégbá orókè tí wọ́n sì gbé òsùbà fún-un níbi ayẹyẹ fífi nǹkan ìsẹ̀mbáyé hàn, léyìí tí ó tún fún àwọn olùkọ eré ní ànfààní…
Ọkọ Fúnkẹ́ Akíndélé Tẹ́lẹ̀ Tùú Nínú Látàrí Ìpapódà Ìyá Rẹ
Olùdarí orin, JJC Skillz ti ránṣẹ́ ìtùnú sí Ìyàwó rẹ̀ àtijọ́ àti ìyá àwọn ọmọ rẹ̀, Fúnkẹ́ Akíndélé.
Èyí rí bẹ nígbà tí Fúnkẹ́ Akíndélé pariwo ikú ìyá rẹ̀ sí ìta.
Ó se àfihàn síta Fídíò tó fi ìgbésí ayé ìyá rẹ̀ hàn, ó kọ́…
Valentine: Àwọn olólùfẹ́ Davido pèsè oúnjẹ fún àwọn aláìní
Àwọn olólùfẹ́ gbajúgbajà akọrin Davido ,gbé ayẹyẹ lọ sí orí títì láti fìfẹ́ hàn sí àwọn ọmọ Nàìjíríà tókù fún ayẹye àyájọ́ olólùfẹ́.
Àwọn olólùfẹ́ Davido lábẹ́ Àsìá 30 Billion Gang, ní ọjọ́…
Fúnkẹ́ Akíndélé Sọ̀rọ̀ Látàrí Ikú Ìyá Rẹ
Oǹdíje igbákejì Gómìnà lábẹ́ ẹgbẹ́ òṣèlú Peoples Democratic Party (PDP) ní Ìpínlẹ̀ Èkó, Funke Akindele ti fọhùn látàrí ikú ìyá rẹ̀ Dokita, RB Adebanjo-Akindele.
Nínú àtẹ̀jáde Instagramu rẹ̀, Funkẹ se ìrántí ìyá rẹ̀ ní ìgbàtí ó…
Emir Kontagora Gba Ọ̀pá Àṣẹ
Gómìnà Abubakar Bello ti Ìpínlẹ̀ Niger ti fún Sarkin Sudan ẹlẹ́ẹ̀kejì ti Ìlú Kontagora, Aláyélúwà Alhaji Muhammed Barau Mu’azu II ní ọ̀pà àṣẹ.
Gómìnà Sanni Bello lo ànfààní ayẹyẹ náà láti pe àwọn Ọba…
Beyonce Fi Ìtàn Balẹ̀ Nípa Gbígba Àmì Ẹ̀yẹ GRAMMY Èkejìlélọ́gbọ̀n
Beyonce ti wá di Oǹkọrin tí ó ti gba àmì ẹ̀yẹ jùlọ nínú ìtàn àmì ẹ̀yẹ gbígbà ti GRAMMY.
Ní ọjọ́ Àìkú, ní ìgbà tí wọ́n ń se ayẹyẹ ẹlẹ́karùn dín láàdọ̀rin irú rẹ̀ ọlọ́dọọdún, ó gba ife ẹ̀yẹ Èkejìlélọ́gbọ̀n gẹ́gẹ́ bí ẹni tó se dáadáa…
Oǹkọrin Ọmọ Nàìjíríà Gbé Àwo Orin Tuntun Jáde Tó Pe Àkọ́lé Rẹ̀ Ní ‘Stand By You.’
Oǹkọrin omọ Naijiria ti gbé àwo orin tuntun jade to pe akole re ni - 'Dúró timi‘. Eléyìí mú kí inú àwọn olólùfẹ́ rẹ̀ dùn jọjọ síi.
Phillip Kayode Moses ni wọ́n bí ní ọjọ́ karún ún oṣù kẹfà ọdún 1994 ní Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.…
Gbajúgbajà Òsèré Orí Ìtàgé Gbé Pẹ́rẹ́gi Ìjà Kaná Pẹ̀lú Ojúgbà Rẹ̀
Gbajúgbajà òsèré orí ìtàgé, Iyabọ Ojo ti fi òpin sí ìbásepọ̀ tí ó wà láàrin òun àti Princess ọ̀rẹ́ ẹ rẹ̀ tẹ́lẹ̀ rí.
Ìgbésẹ̀ náà wáyé lẹ́yìn ìgbà tí Halima fi ọ̀rọ̀ wá Princess lẹ́nu wò, Ó fi ẹ̀sùn…
Akọrin Amẹ́ríkà Snoop Dogg fìfẹ́ẹ̀ hàn láti kọrin pẹ̀lú Tems
Akọrin Amẹ́ríkà tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Snoop Dogg ti fihàn gbangba sí Akọrin ìlú mọ̀ọ́ká Nàìjíríà Tems, pé òun fẹ́ kí wọ́n jọ kọrin papọ̀.
Snoop Dogg fi èyí ránsẹ́ sórí ayélujára Instagram Tems, tí Tems náà sì fi…
Ìjọba Ìpínlẹ̀ Èkó Sàfirinlẹ̀ Àtìlẹyìn Fún Àwọn Ọlọ́pọlọ Pípé Ẹ̀dá
Ìjọba ìpínlẹ̀ Èkó se àfirinlẹ̀ ìfarajì rẹ̀ láti se àtìlẹyìn fún àwọn ọ̀dọ́ jákè-jádò ìpínlẹ̀ fún ìdàgbàsókè ẹ̀bùn ọpọlọ wọn.
Olùdámọ̀ràn pàtàkì sí Gómìnà lórí àsà, Ọ̀gbẹ́ni Fẹmi Martins…