Take a fresh look at your lifestyle.

Òṣèré Tíátà Abubakar Yakubu Bẹ̀rẹ̀ Isẹ́ Gẹ́gẹ́ Bíi Ọgá Tuntun Fún Ẹgbẹ́ AGN.

486

Ẹgbẹ́ òṣèré ti wọn n pé ni Actor Guild Of Nigeria AGN ti ki Ààrẹ tuntun káàbò sí ẹnu iṣẹ Abubakar Yakubu ni ìlu Abuja.

Ìròyìn fi yè wa wí pè Ààrẹ tuntun náà búra láti bẹ̀rẹ̀ isẹ́ ni ilè iṣẹ́ AGN ni ìlu Abuja.

Yakubu ló bo sí ipò lẹyìn ìgbà ti Emeka Rollas gbé ipo kalẹ fún lẹyìn ìgbà ti akọkọ rẹ ti pe ni osu Kejìlá ọdun 2025..

Ifini sí ipò náà mu ki ẹsẹ̀ gbogbo àwọn òṣeré péjú, bákanáà àwọn tọrọ kan ati àwọn ènìyàn jakanjakan láti lé ṣe ajoyọ

Ààrẹ tuntun náà sí ṣe ìlérí láti ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bí ẹgbẹ́ ti fe ati lati mu ìdàgbàsókè bá ẹgbẹ́ AGN lápapò.

Comments are closed.

button