Take a fresh look at your lifestyle.
Browsing Category

ÌRÒYÌN ÌDÁNILÁRAYÁ

This is a category for entertainment news

Ààrẹ Tinubu Gbóríyìn Fún Àwọn Tí Wọn Yan Láti Gbà Àmì Ẹ̀yẹ àgbáyé Àwọn Olórin.( Grammy).

Ààrẹ Bọla Ahmed Tinubu ti ki àwọn  ọmọ Olorin Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ti wọn yan mọ àwọn Olorin àgbáyé míràn  lati gbà àmì ẹ̀yẹ àgbáyé fún àwọn Olorin. Ààrẹ ní èyí tunmọ sí wí pé wọn ṣiṣẹ takuntakun lati rí wí wọn fi iṣẹ orin tun ayé àwọn…

Ìgbà Kòtọ́ Lọ Bí Òréré, Ayé Kò Tọ́ Lọ Bí Ọ̀pá Ìbọn, Kizz Daniel Rántí Ìgbà Tí Ó Ń…

Akọrin Ọmọ Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, Oluwatobilọla Daniel Anidugbe tí gbogbo ayé mọ̀ sí Kizz Daniel se ìrántí àsìkò kan tí ó n siṣẹ́ ni ilé iṣẹ́ ìtẹ̀wé, ní ìlú Abẹokuta níbi tí ó ti n gba ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ̀jọ ẹgbẹ̀rún…
button