Take a fresh look at your lifestyle.
Browsing Category

ÌRÒYÌN ÌLERA

This is a category for health news

Ìyanṣẹ́lódì àwọn dókítà: A ti Ṣe àṣeyọrí tó nítumọ̀ -–Mínísítà ètò Iṣẹ́

Ìjọba orílẹ̀ -èdè Nàìjíríà sọ pé òhun ti yanjú gbogbo àwọn nǹkan  tí àwọn dókítà Oníségùn ń bèèrè fún, àyàfi èyí tí ó lòdì sófin “kò sí iṣẹ́  kò sáwó”. Nitorinaa, ijọba n kepe awọn ọmọ ẹgbẹ dokita…

Ènìyàn méjì- lé- lọ́tà- lélọ́ọ̀dúnrún míràn tún ti ní ààrùn covid

Ní ọjọ́ àìkú,ọjọ́ kọkàn – dín – lọ́gbọ̀n oṣù kẹjọ,ọdún 2021, àwọn ènìyàn méjì- lé –lọ́tà –lélọ́ọ̀dúnrún míràn tún ti ní ààrùn covid, gẹ́gẹ́ bí ilé – iṣẹ́ tó ń mójútó àjàkálẹ̀ ààrùn ṣe kéde rẹ̀ ní…

Ìjọba Nàìjíríà ṣe ìlérí pé òhun yóò jẹ́ kí abẹ́rẹ́ àjẹsára covid wà lárọ̀wọ́tó

Ìjọba orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ti ṣe ìlérí láti ríi dájú pé  abẹ́rẹ́ àjẹsára covid wà lọ́pọ̀ yanturu jákèjádò orílẹ̀-èdè náà. Akọwe  ijọba apapọ ati alaga,igbimọ alakoso aarẹ lori aarun covid,Boss Mustapha,fidi…