Take a fresh look at your lifestyle.
Browsing Category

ÌRÒYÌN ÌLERA

This is a category for health news

Àwọn Ènìyàn Tó Tó Ẹgbẹrun Mẹ́fà Lo Jẹ  Anfààní Ètò Ìtọjú Ìlera Ọ̀fẹ́ Ni Ìpínlẹ̀ Imo.

Ó kéré jù àwọn ẹgbẹrun mẹ́fà ènìyàn ní yóò jẹ anfààní ètò ìtọjú ìlera Ọ̀fẹ́ ni ìpínlẹ̀ Imo èyí tí Mbana National Assembly gbé kalẹ. Wọn ni yóò tó ọgọrùn mílíọ̀nù méjì náírà ni wọn gbé kalẹ fún ètò náà. Ìtọjú Ọ̀fẹ́ náà wáyé ní ilé ìwòsàn…
button