Browsing Category
ÌRÒYÌN ÌDÓKOÒWÒ
This is a category for business news
Orílẹ̀-èdè Algeria Yóò Rí Bílíọ̀nù Mẹ́ta Dọ́là Owó Ẹ̀yá Gbà Láti Ọ̀dọ̀ Báǹkì Ìdàgbàsókè Ìsìláàmù
Ààrẹ Banki Idagbasoke Isilaamu - "Islamic Development Bank" Muhammad Sulaiman Al Jass ti sọ pé Orílè-èdè Algeria yoo ri Biliọnu Mẹta Owó dọ́là ya laarin odun mẹta tẹ̀léra lati fi ṣe àwọn àkànṣe iṣẹ ìdàgbàsókè.
Ààrẹ ilè…
Ilé Ifowopamọ ECOWAS Ti Ṣetán Láti Sí Ilè Ifowopamọ Si Orílè-èdè Cote d’voire.
Ilé Ifowopamọ ECOWAS fún ìdọ́kọ̀wọ̀ àti ìdàgbàsókè ti buwolu ìwé ajọṣepọ láti da ilé iṣé silẹ ni Orílẹ̀-èdè Cote d'Ivoire.
Ni ìlú Abidjah ni ọrọ àjọsọpọ tó dan mọ́rán yii wáyé láàárín ìjọba Orílẹ-èdè Cote d'Ivoire èyí tí Mínísítà fún òrò…
Owó Orí Ọjà Amẹ́ríkà Dẹ́rùba Ọrọ̀ Ajé Ilẹ̀ Adúláwọ̀ -Akọ́sẹ́mọsẹ́ Ọmọ Orílẹ̀-èdè Màláwì
Owó orí ọjà Amẹ́ríkà lórí ọrọ̀ ajé ọ̀pọ̀lọpọ̀ orílẹ̀-èdè ilẹ̀ Adúláwọ̀ sàkóbá bá ọrọ̀ ajé wọn, orílẹ̀-èdè Màláwì jẹ́ ọ̀kan, akọ́sẹ́mọ́sẹ́ nípa ọ̀rọ̀ òṣèlú-Maclan Kanyang’wa sọ èyí.
Ó sọ pé, oye owó tí wọ́n ń ta nǹkan ní…
Lójúnà Àti Sọ Ayé Di Gbẹdẹmukẹ, Ìjọba Ìpínlẹ̀ Kwara Se Àtìlẹyìn Fún Ará Ìlú
Ìjọba Ìpínlẹ̀ Kwara fi àrídájú hàn sí àwọn olùgbé Ìpínlẹ̀ náà wípé jíjẹ mùdùn-múdùn ìdókoòwò ìjọba yóò tẹ̀síwájú èyí tí yóò sọ ayé di gbẹdẹmukẹ ní Ìpínlẹ̀ Kwara
Alága Ètò Ìdókóòwò ní…
Aṣòfin Oluremi Tinubu Pé Fún Ìfọwọ́sowọ́pọ̀ Olori Ìlú Láti Fòpin Sí Dídá Abẹ Fún Ọmọbìnrin (FGM)
Àyà Ààrẹ Orilẹ Èdè Nàìjíríà, Aṣòfin Oluremi Tinubu ti ké sí àwọn Olórí ìlú àti agbègbè láti sa ipá wọn lójúnà àti fi òpin sí dídá abẹ fún ọmọ obìnrin (FGM), kòkòrò HIV/AIDS àti àrùn jẹ̀dọ̀jẹ̀dọ̀.
Oluremi Tinubu lo fi ọ̀rọ̀ lédè lásìkò tó…
Ààrẹ Bola Tinubu tí kí Ààrẹ Ẹgbẹ́ Dangote, Alhaji Aliko Dangote, lórí yíyàn rẹ̀ sí ilé-iṣẹ́ ìdókòwò…
Ààrẹ Bola Tinubu tí kí Ààrẹ Ẹgbẹ́ Dangote, Alhaji Aliko Dangote, lórí yíyàn rẹ̀ sí ilé-iṣẹ́ ìdókòwò aládàáni ti banki àgbáyé.
Ilé-iṣẹ́ Ìdókòwò Aládàáni tí Bánkì Àgbáyé jẹ́ 'apá kán tó níí ṣé pẹ̀lú ìgbéga ìdókòwò àti ṣiṣẹda iṣẹ́ ní àwọn…
GENCOS Dúnkookò Òkùkùn Biribiri Látàrí Gbèsè Àwọn Oníbàáárà
Àjọ Gencos ní Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ti palrọwà sí ìjọba àpapọ̀ àti àwọn alẹ́nulọ́rọ̀ láti wá ojútùú sí ìsòro gbésè iná mọ̀nàmọ́ná tí wọ́n pèsè àti èyí tí àwọn oníbàáárà rẹ̀ lò
Alága Àjọ…
Makinde Ke Sí Ọmọ Orílẹ̀ Èdè Nàìjíríà Láti Wá Dá Okòwò Sílẹ̀ Ní Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́
Gómìnà Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́, Seyi Makinde ti ké sí ọmọ Orílẹ̀ Èdè Nàìjíríà láti wá da okòwò sílẹ̀ ní Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́, nígbà tó fìdí rẹ̀ múlẹ̀ pé Ìpínlẹ̀ náà wà lójú iṣẹ́ lójúnà àti mú kí ọrọ̀ àjé gbèru síi nípasẹ̀ ètò ìgbáyé-gbádùn.
Makinde ló fìdí…
Àjọ SON Fún Ilé Iṣẹ́ Tó Wà Ní Anambra Ní Ìwé Ẹ̀rí
Àjọ Standards Organisation of Nigeria (SON) ti fun Ile iṣẹ mẹ́rìnlélógójì ní ìwé èrí Mandatory Conformity Assessment Programme (MANCAP) moyege.
Wọ́n pín ìwé ẹ̀rí náà ní ọjọ́ Ọjọ́bọ̀ ní ìlú Awka, Dókítà Ifeanyi Okeke tó jẹ…
Ìdókòwò Alábọ́dé Ni Ọ̀pákùtẹ̀lẹ̀ Ọrọ̀ Ajé Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà – Mínísítà Jumokẹ…
Mínísítà Fún Ilé Iṣẹ́, Òwò àti Ìdókòwò ti sàfirinlẹ̀ ipa tí ìsòwò alábọ́dé ńkó gẹ́gẹ́ bí ọ̀pákùtẹ̀lẹ̀ èyí tí ó ń mú ìdàgbàsókè bá ètò ọrọ̀ ajé Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà
Nígbà tí ó ń sọ̀rọ̀…