Take a fresh look at your lifestyle.

‎Ìgbìmọ̀ Àwọn Gómìnà Fọwọ́sí Súgà Gẹ́gẹ́bí Ọjà Pàtàkì Fún Ìpèsè Ìṣẹ́

Ìgbìmọ̀ àwọn Gómìnà Nàìjíríà (NGF) ti gbà láti fi súgà sí ipò pàtàkì gẹ́gẹ́ bí ọjà Ilé-iṣẹ́ tí yóò mú kí ìdàgbàsókè àwọn ilé-iṣẹ́ yára kárí àwọn ìpínlẹ̀, èyí tí yóò ṣe àtìlẹ́yìn tuntun fún pi pèsè àwọn òun èlò aráàlú láti inú Orílẹ̀-èdè…

Mínísítà Rọ Àwọn Oníròyìn Láti Mú Ìṣọ̀kan Àti Ìtọ́sọ́nà Lágbára Si

Mínísítà fún Ìròyìn àti Ìtọ́sọ́nà Orílẹ̀-èdè, Mohammed Idris, tí rọ àwọn olùdarí àti àwọn òṣìṣẹ́ ìròyìn ní àwọn ilé-iṣẹ́ ìròyìn tí ìjọba láti ṣe ìtọ́sọ́nà tó lagbara, ìṣọ̀kan àti oye tó ga jùlọ hàn nìdí iṣẹ́ wọn, O sọ pé ìròyìn wọn tó múná…

Nàìjíríà Ti Múra Tán Láti Ṣe Àtúnṣe Ọjọ́ Iwájú Áfíríkà Nípasẹ̀ Ìfọwọ́sowọ́pọ̀ – VP Shettima

Igbákejì Ààrẹ Kashim Shettima ti tún sọ ìpinnu Nàìjíríà láti ṣe àtúnṣe ọjọ́ iwájú Áfíríkà nípasẹ̀ ipa, ìfọwọ́sowọ́pọ̀, àti ìdókòwò. ‎ ‎ Láti ṣàṣeyọrí èyí, ó sọ pé orílẹ̀-èdè náà ń ṣe ìfilọ́lẹ̀ àti láti mú kí àwọn ètò bíi Ìṣọ̀kan Iṣòwò fún…

Mínísítà Fún Ètò Ọmọnìyàn Wàásù Ìṣọ̀kan Fún Àwon Alẹ́nu-lọ́rọ̀ Àríwá Plateau

Mínísítà fún Ètò Ọmọnìyàn àti Ìdínkù Òṣì ní Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, Dókítà Bernard Doro, tí pé ìpàdé gbogbogbò àwọn alẹ́nu-lọ́rọ̀ agbègbè Àríwá ní Ìpínlẹ̀ Plateau. O ń pé fún ìṣọ̀kan, ìdàgbàsókè ìkópa nínú ètò òṣèlú àti àlàáfíà bí ẹgbẹ́ òṣèlú…

Àwọn Aṣojú Ìrètí Tuntun Ṣe Ìfilọ́lẹ̀ Àwọn Olùṣàkóso Ìbílẹ̀ Ní Sokoto

Ẹgbẹ́ Àwọn Aṣojú Ìrètí Tuntun ti Ìpínlẹ̀ Sokoto ti ṣe ìfilọ́lẹ̀ àwọn olùṣàkóso ìbílẹ̀ mẹ́tàlélógún láti darí ìgbòkègbodò ètò náà káàkiri ìpínlẹ̀ náà. ‎ ‎Ayẹyẹ ìfilọ́lẹ̀ náà, tí a ṣe ní Sokoto, ṣe àmì ìgbésẹ̀ pàtàkì láti fún ìgbìmọ̀ náà…

Ìgbìmọ̀ Ìrètí Tuntun Ń Tẹ̀síwájú Lórí Kíkópa Àwọn Ọ̀dọ́ Nínú Ìṣàkóso – Kọmíṣọ́nà

Alaga, Ìgbìmọ̀ Àwọn Kọmíṣọ́nà Ìpínlẹ̀ Nasarawa àti Kọmíṣọ́nà fún Àyíká àti Àwọn Ohun Àlùmọ́nì, Dókítà Margaret Elayo, ti sọ pé ètò Ìrètí Tuntun ti Ààrẹ Bola Tinubu ni a ṣe láti fún àwọn ọ̀dọ́ Nàìjíríà lágbára gẹ́gẹ́ bí àwọn aṣáájú lónìí àti…

Àwọn Alábàáṣiṣẹpọ̀ NUJ FCT So ìbáṣepọ̀ Pẹ̀lú Ilé-iṣẹ́ Tayan Lórí Ilé Gbígbé, Gbọ̀ngàn Àpérò ‎

Ẹgbẹ́ Àwọn Oníròyìn Nàìjíríà (NUJ), tí Olú-ìlú, Abuja, ti wá àjọṣepọ̀ pẹ̀lú 'Tayan Group Construction' láti gbé ilé tó rọrùn fún àwọn oníròyìn lárugẹ àti láti mú kí iṣẹ́ àgbékalẹ̀ Gbọ̀ngàn Àpérò tuntun wọn yára kánkán ní Abuja. ‎ ‎ Ẹ̀bẹ̀…
button