Take a fresh look at your lifestyle.
Browsing Category

ÌRÒYÌN ÌDÁRAYÀ

This is a category for sport news

Ẹgbẹ́ agbábọ̀ọ̀lù Nàìjíríà (Flamingo) gba ipò kẹta mọ́ Germany lọ́wọ́ lẹ́yìn tí wọ́n gbo…

Ẹgbẹ́ agbábọ̀ọ̀lù obìnrin orílẹ̀-èdè Nàìjíríà U-17, Flamingos fi àgbà han ẹgbẹ́ agbábọ̀ọ̀lù Germany pẹ̀lú àmì ayò pẹnátì mẹ́ta sí méjì lẹ́yìn tí wọ́n jọ fakàngbọ̀n lóri pápá pẹ̀lú àmì ayò mẹ́ta-mẹ́ta, èyí…

Ìdíje Ife Ẹ̀yẹ Eré Bọ́ò̩lù Ilẹ̀ Áfíríkà – Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ Ṣèlérí Ètò Ààbò Tó Dájú

Kọmisana fún ọrọ Ọdọ ati Eré Ìdárayá ni ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́, Seun Fakorede ti fi ìdí rẹ̀ múlẹ pé àjọ tó n ṣe àkóso ere bọọlu alafese gba ní ilẹ Áfíríkà, CAF ati àjọ tó n ṣe àkóso idije ere bọọlu ni orílè èdè Nàìjíríà, NFF ti ṣe eto gbogbo fún…

Indian 2022: Ẹgbẹ́ agbábọ̀ọ̀lù Obìnrin Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà (U-17) gbìyànjú ṣùgbọ́n omí pọ̀ ju ọkà lọ…

Ẹgbẹ́ agbabọọlu Obirin U-17 ti Naijiria, Flamingos, ti já kúrò nínú ìdíje FIFA U-17 ife àgbáyé, ọdún 2022 nipasẹ fífi ìdí rẹ mi nínú eré bọọlu pẹlu awọn agbábọ̀ọ̀lù Colombia wọn gbìyànjú diẹ ṣugbọn ìgbìyànjú wọn kò tó, won jẹ àmì ayo mẹfa…