Ọ̀jọ̀gbọ́n Osinbajo Gbóríyìn Fún Akitiyan Àwọn Ọ̀dọ́ Nàìjíríà
Igbákejì Ààrẹ Nàìjíríà, Ọ̀jọ̀gbọ́n Yemi Osinbajo sọ pé ìgbìyànjú àìlópin, akitiyan àti ọgbọ́n àwọn ọ̀dọ́ ni ó ti jẹ́ ìdánilójú fún òhun pé Nàìjíríà yóò ní ìlọsíwájú; àti wípé ìpèsè iṣẹ́ fún…