Browsing Category
Uncategorized
Ẹ̀pa Ò Gbóró Fún Orílẹ̀-èdè Cameroon, Bí Orílẹ̀-èdè Nàíjíríà Ṣe Lé Wọn Padà Lọ Sí Ìlú Wọn Pẹ̀lú…
Super Eagles àti Àwọn agbabọọlu Cameroon tí a tun mọ wọn sí Indomitable Lion bẹrẹ ere bọọlu ti ipele ofìdí rẹmi, o gba ilé rẹ̀ẹ lọ ti ẹlẹyinbo n pe n Knock Out ní dede aago mẹsan-an alẹ́
Ajayi ọmọ ẹgbẹ́ Agbábọ̀ọ̀lù Super Eagles lo…
Akọ̀wé America Yín Ìbáṣepọ̀ Orílẹ̀-èdè Rẹ̀ Pẹ̀lú Angola
Akọ̀wé tí America Antony Blinken tí yín ìbáṣepọ̀ láàrín Orílẹ̀-èdè America àti Orílẹ̀-èdè Angola, Ó sọ pé ìbáṣepọ̀ náà tí dé ibì gíga, Ó sọ èyí làkókò àbẹwò rẹ̀ sí Luanda.
Blinken sọ pé òun tí jíròrò lórí rògbòdìyàn tó wà láàrín Rwanda…
Ilé Iṣẹ́ Ọkọ̀ Òfúrufú Boeing Gbà Pé Àwọn Se Àsìse Látàrí Ilẹ̀kùn Tó Fò Yọ
Ọgá Ilé Iṣẹ́ Ọkọ̀ Òfurufú Boeing ti sọ pé awon gba pe àwọn se àsìse látàrí ilẹ̀kùn tó fò yọ ni kété ti ọkọ Òfúrufú gbéra ni orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà.
Bótilẹ̀jẹ́pé kò sí ẹni tó fára pa nígbà tí ìsèlè náà ṣẹlẹ̀ ni ọjọ́ Ẹtì. Ìjọba…
Wọ́n Ṣé Ìwọ́de Kẹdùn Àwọn Ọmọ Orílẹ̀-èdè Palestine Ní Casablanca
Àwọn aráàlú Morocco ṣé iwọde ní àtìlẹ́yìn àwọn ọmọ orílẹ̀-èdè Palestine ní Casablanca, wọ́n n pé láti fòpin sí rògbòdìyàn Gaza, kí ìjọba Orílẹ̀-èdè Morocco sí fòpin sí ìbaṣepọ̀ wọ́n pẹ̀lú Israeli.
Ẹgbẹẹgbẹ̀rún lọ́nà ẹgbẹẹgbẹ̀rún ló gba…
Ẹgbẹ́ Aláàdáni Rọ Ìjọba Ìpínlẹ̀ Eko Láti Fàyè Gba Ètò Ìdìwò Nípa Ìlera.
Ẹgbẹ́ Aláàdáni lórí ọ̀rọ̀ ìlera, ti rọ ìjọba ìpínlẹ̀ Eko láti faye gba ètò Ìdìwò nipa ìtọjú ìlera, wọn ní eleyii yóò mú kí àwọn tó kún diẹ fún leè ba tójú ara wọn
Ọ̀rọ̀ yìí jáde níbi ìpàdé àwọn òṣìṣẹ́ ìlera ní Ikeja ni ilu Eko
Ààrẹ…
Ilé-ìgbìmọ̀ Aṣòfin ECOWAS Pé Fún Ìgbìyànjú Látí Kojú Ìpènijà Ààbò
Ilé-ìgbìmọ̀ Aṣòfin tí àwọn Orílẹ̀-èdè ní Ìwọ̀-oòrùn Áfíríkà (ECOWAS), tí bẹ̀rẹ̀ ìpàdé Aṣojú Kejì rẹ̀ tí ọdún 2023, pẹ̀lú ìpè fún ètò ìdáàbòbò àyíká àtí àgbègbè láti kojú Ìpènijà ààbò àgbègbè náà.
Àpéjọ náà tún wà fún ìjíròrò lórí àwọn…
Ààrẹ Tinubu Gbàdúrà Fún Àwọn Ènìyàn Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà Ni Saudi Arabia.
Ààrẹ Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà Bola Ahmed Tinubu ti gbàdúrà fún àlàáfíà àti ìdàgbàsókè Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà àti fún gbogbo àwọn ènìyàn nbè.
Ààrẹ to wà ni ìlú Mecca báyìí ni Orílẹ̀-èdè Saudi Arabia láti lo gbàdúrà fún àwọn ọmọ Orílẹ̀-èdè…
Ààrẹ Tinubu buwọ́lu ìdásílẹ̀ àwọn ilé-èkọ́ gíga tuntun méje
Ààrẹ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, Bọla Ahmed Tinubu ti buwọ́lu ìdàsílẹ̀ àwọn ilé-èkọ́ gíga tuntun méje lórílẹ̀-èdè ní kíákíá láti túnbọ̀ jẹ́ kí ètò ẹ̀kọ́ tó yè koro wà lárọwọ́tó fún àwọn ènìyàn.
Iyipada…
Makinde Kẹ́dùn Ikú Ọba Àwọn Ẹ̀yà Ìgbò Ni Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́
Gómìnà Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́, Seyi Makinde ti kẹ́dùn ikú Eze Ndigbo Ilẹ Ìbàdàn, Omowe Alex Anozie tíì ṣe Oba àwọn ẹ̀yà Ìgbò to wa ni Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́, to sì ṣe àpèjúwe ikú rẹ̀ gẹ́gẹ́ bíi ohun tó dunni jọjọ.
Gómìnà, ẹni tó ránṣẹ́ ìbánikẹ́dùn yìí…
Ẹgbẹ́ Àwọn Oníròyìn VON Ké Gbàjarè Síta Bí Wọ́n Ṣe Pàdánù Ọ̀kan Lára Àwọn Akọ̀ròyìn Wọn, Hamisu…
Pẹ̀lú Ibanujẹ Ọkàn ni Ẹgbẹ́ Àwọn Oníròyìn VON gba iroyin Ibanujẹ ikú Hamisu Danjigba, Akoroyin fún Ilé Akede Nàíjíríà (VON) ní Ìpínlẹ̀ Zamfara, iṣẹlẹ ibanujẹ yii to ṣele láti ọwọ́ àwọn ajínigbé.
Ikú rẹẹ̀ jẹ nkan Ibanujẹ tó tún ran wa létí…