Take a fresh look at your lifestyle.
Browsing Category

ÌRÒYÌN ORÍLẸ̀-ÈDÈ NÀÍJIRÍÀ

This is a Nigeria news category

Àdínkù owó epo ilẹ̀: Ìjọba Nàìjíríà ṣèpàdé pẹ̀lú ìgbìmọ̀ ẹgbẹ́ kátàkár̀a

Ìjọba Nàìjíríà n ṣepade pẹ̀lú àwọn aṣojú ìgbìmọ̀ ẹgbẹ́ kátàkár̀a (TUC), lọ́wọ́ báyìí, ní gbọ̀ngàn ààrẹ, ní  Villa, Abuja. Ìpàdé tó bẹ̀rẹ̀ ní dédé agogo mẹ́rin ìrọ̀lẹ́, yóò dá lórí ìfọ̀rọ̀jomitoro ọ̀rọ̀…

Ìgbòkègbódò Ọkọ̀: Ìjọba Ìpínlè Ọ̀yọ́ Yan Alága Àti Akọ̀wé Ẹgbẹ́ ‘PMS’ Tuntun

Ìjọba Ìpínlè Ọ̀yọ́ labẹ àkóso Gómìnà Seyi Makinde tí yan Alhaji Oluwatomiwa Omolewa gẹgẹ bíi Alága tuntun fún Ìgbìmò to n ṣàkóso Ibùdókọ̀ (PMS). Bákan náà ní ìjọba yan Alhaji Kasali Ajisafẹ, ti wọn mọ sí 'Baba Bola' gẹgẹ bíi Akọwe ẹgbẹ́.…

Agbófinró da àwọn òṣìṣẹ́ síta láti fòpin sí àṣẹ kónílé ó gbélé IPOB

Kọmíṣọ́nà Agbófinró ti ìpínlẹ̀ Enugu , Ọ̀gbẹ́ni Ahmed Ammani, ti da àwọn òṣìṣẹ́, àwọn ohun èlò ìṣiṣẹ́ àti ti ìṣiṣẹ́ ọpọlọ láti pèsè ààbò, ní ọjọ́ Ajé àti gbogbo ọjọ́ ní ìpínlẹ̀ náà. Eléyìí wá lẹ́yìn àṣẹ…

A Ní Láti Bẹrẹ Ìgbésẹ̀ Àtúnṣe Ẹgbẹ́ Òṣèlú PDP Báyìí: Makinde Sọ Fún Àwọn Èèkàn Ẹgbẹ́

Gómìnà Ìpínlẹ̀ Òyó Seyi Makinde tí ké sí gbogbo àwọn èèkàn ti ọrọ Ẹgbẹ́ Òṣèlú PDP jẹ lógún láti gbàgbé ìkùnsínú àtẹ̀yìnwá, ki wọn ṣetán láti ṣe àtúnṣe, ki wọn sì ṣiṣẹ papọ̀ fún iṣọkan ẹgbẹ́ náà. Àtẹ̀jáde kan tí Akọwe ìròyìn fún Gómìnà,…

Ìpínlẹ̀ Anambra : Igbákejì ọ̀gá Agbófinró fi ìrànlọ́wọ́ rẹ̀ dá àwọn agbègbè lójú

Igbákejì ọ̀gá Agbófinró, AIG, Ọ̀gbẹ́ni Tony Olofu tí ó ń ṣojú olú ilé-iṣẹ́ agbègbè kẹtàlá, ní Ukpo, ìpínlẹ̀ Anambra, ti fi dá àwọn agbègbè ní ìpínlẹ̀ náà lójú pé òun yóò ṣèrànlọ́wọ́ fún wọn. AIG ṣe…