Take a fresh look at your lifestyle.
Browsing Category

ÌRÒYÌN ÈTÒ Ọ̀GBÌN

Àwọn Tí Ó Ń Fi Owó Ṣe Ìrànlọ́wọ́ Fún Àwọn Ènìyàn Ṣe Ìrànlọ́wọ́ Fún Àwọn Àgbè Ni Ìpínlẹ̀ Enugu.

Ọgá àgbà pátápátá fún ilẹ iṣé Paschal -Rico, Olóyè Pascal Aneke àti Ọ̀gbẹni Sunday Ozokolo láti Orílẹ̀-èdè Switzerland ni ọjọ́ ìsinmi Pin àwọn ohùn èlò ìrànlọ́wọ́ fún àwọn àgbẹ̀ ìgbèríko ni ìjọba ìbílẹ̀ Ezeagu ni Ìpínlẹ̀ Enugu. Àwọn…

Àwọn Àgbẹ̀ Òní kòkó Ti Ìpínlẹ̀ Ondo Fí Ẹ̀dun Ọkàn Wọn Hàn Látàrí Bí Àwọn Onísé Láabi Ṣe N Dá Wọn…

Àwọn àgbẹ̀ ọ̀gbìn kòkó ni ìpínlẹ̀ Ondo ni agbègbè Odigbo ni oko ti wọn pe Oluwa Forest ,ti fi ẹ̀dun ọkàn  wọn ní hàn látàrí bi àwọn oníṣe láabi se n dá wọn Láàmú ninu oko Wọn ní àkolù yìí bẹ̀rẹ̀ láti ìgbà tí ilé ẹjọ ti ṣe ìdájọ lori ìja…

Ilé iṣé Ìjọba Ti Ìpínlẹ̀ Kwara Se Ìdánilẹ́kọ̀ọ́ Fún Awọn Àgbẹ̀ Nípa Ọ̀gbìn Ẹ̀gẹ́.

Ó lẹ ní àádọ́ta àwọn àgbẹ̀ àti àwọn ènìyàn tí ó kópa nínú ìdánilékòó nípa ẹ̀gẹ́ gbin gbìn èyí wáyé láti mú ìdàgbàsókè bá ètò ounjẹ ni Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Ilé iṣé Ìjọba fún ètò ọgbin àti oúnjẹ ní o ṣe agbáterù ètò náà àti ìbáṣepọ̀ ìjọba…
button