Take a fresh look at your lifestyle.

Ìgbìmọ̀ Ẹgbẹ́ Òṣèlú PDP Ṣe Ìlérí Láti Jẹ Agbára Fún Ẹgbẹ́ Náà.

74

Ìgbìmọ̀ Ẹgbẹ́ Òṣèlú PDP ti ṣe ìlérí láti ṣiṣẹ takuntakun fún igbedide àti òkun fún ẹgbẹ́ òṣèlú PDP.

Gómìnà ìpínlẹ̀ Bauchi tó tún jẹ Alága fún ìgbìmọ̀ ẹgbẹ́ òṣèlú PDP Bala Mohammed lo sọ èyí di mímọ nígbà tí o n ba àwọn oníròyìn sọrọ lẹyìn ìpàdé ní ìlú Abuja.

Ó ní àwọn ṣe ìpàdé lorisirisi bi ìlọsíwájú àti àtúnṣe yóò ṣe ba ẹgbẹ́ náà

Ó ní àwọn ọnà abayọ sí Ìpẹ̀níjà lórí ẹgbẹ́ PDP ni  àwọn tun gbé yẹ wò fún àtúnṣe

Comments are closed.