Take a fresh look at your lifestyle.

Igbákejì Ààrẹ Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà Dé Sí Ìpínlẹ̀ Jigawa.

57

Igbákejì Ààrẹ Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà Kasham Shettima bro kalẹ báyìí sí ìpínlẹ̀ Jigawa fún ibẹwo ọlọkàn.

Pápákọ̀ òfurufú Dutse ni wọn ti lo ṣe ìkíni káàbọ̀ igbákejì Ààrẹ ni dédé àgọ mẹwàá kọjá iṣẹju márùn owurọ̀.

Igbákejì Ààrẹ ni àlejò pàtàkì níbi  Ìfinijóyè Alhaji Nasiru Haladu Danu gẹ̀gẹ̀ bi SARDANH ti DUSE.

Bákanáà Ààrẹ yóò ṣe àwọn Akose iṣé ní ìpínlẹ̀ Jigawa kò to di wí pé yóò padà

Comments are closed.