Take a fresh look at your lifestyle.

Ààrẹ Buhari di adarí ẹgbẹ́ PAGGW

115

Ààrẹ Muhammadu Buhari  kò ni pẹ́ di adari ẹgbẹ́  (PAGGW) ni oṣu kẹsan an, ọdun 2021.
PAN-GGW, jẹ  ẹgbẹ́ tiwọn gbé kalẹ̀ lati mu iyipada rere bá àwọn ilẹ Afirika ati lati  mu ipinnu wọn sẹ latí yí  ìgbésí ayé miliọnu awọn eniyan  padà.

Minisita fun eto ayika lorilẹ -ede Naijiria, Mohammad Abubarka lo salaye yii   fun awọn oniroyin niluu Abuja lori awọn idagbasoke  ti ajọ rẹ ti se ní  ẹ̀ka ayika, paapaa julọ lorilẹ ede Naijiria.   O  tẹsiwaju pe ipa pataki ti orilẹ-ede Naijiria ń kó lati koju iyipada ojú-ọjọ́ ati gbigbogun ti  awọn ibajẹ nipa ti ayika , yii ni o fun aarẹ ni anfaani lati jẹ adari ẹgbẹ́  Pan-Afirika (PAGGW).

Leave A Reply

Your email address will not be published.