Take a fresh look at your lifestyle.

Ẹ̀yin ọ̀dọ́ , ẹ lọ́wọ́ sí òsèlú Naijiria

0 264

Igbakeji aarẹ orile ede Naijiria, ọjọgbon Yemi Osinbajo  ti rọ awọn ọdọ orilẹ ede Naijiria ki wọn tubọ maa lọwọ ninu oselu orilẹ ede yii nitori pe gbogbo eniyan ni oselu wà fun.

Osinbajo sọrọ yii lọjọ Aje lasiko ayẹyẹ ìfì̀wé lọ́lẹ̀ ti wọn pe ni :  “Oselu to wulo: Ohun ti ile -iwe ati ibi  àpéjọ ko ni kọ yin lati jawe olubori ninu eto idibo  ,” Awọn ọnkọwe naa ni  oluranlọwọ aarẹ  Babafemi Ojodu ati Alex Adekunle James.

Igbakeji aarẹ , Osinbajo tun sọ pe owo tun jẹ ọkan  lara  isoro to n dojukọ awọn ọdọ lati maa lee lọwọ ninu eto iselu .

Ojodu naa wa rọ awọn ọdọ lati maa lọwọ ninu eto iselu nitori pe kii se gbogbo nnkan ni agídí , jagidijagan ati wahala ma n se.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button