Take a fresh look at your lifestyle.

Amnesty International kò ní ẹ̀tọ́ lábẹ́ òfin láti wà lórílẹ̀-èdè Nàíjíríà – Garba Shehu

100

Ijọba orilẹ ede Naijria ti bu ẹnu atẹ lu ọrọ ti ẹgbẹ Amnesty International ( A-ja fẹtọ-ọmọniyan lagbaaye) sọ nipa  orilẹ ede Naijiria ,ijọba sọ pe  “Wón ti pinnu lati maa gbe lẹ́yìn awọn ọlọtẹlai bikita fun awọn eniyan ti awọn ọdaran yii ti se ni ijamba tabi ti wọn ti fi ẹ̀mí wọn sòfò.’’

Oluranlọwọ pataki fun aarẹ lori iroyin ati ikede fun aarẹ Buhari , Garba Shehu lo sọrọ yii niluu Abuja.

Garba Shehu tun wa tẹsiwaju pe  “ijọba ko ni kaarẹ lati maa gbogun ti aọn ọlọtẹ ati ọdaran to n da omi alaafia orilẹ ede Naijiria rú, bo se wu ki awọn kan maa sọ ahesọ ọrọ lati tabuku ijọba orilẹ ede yii.”

 

 

Leave A Reply

Your email address will not be published.