Take a fresh look at your lifestyle.
Browsing Category

Uncategorized

Sunday Igboho:Ilé-ẹjọ́ gíga ti ìjọba àpapọ̀ fàáké kọ́rí láti sègbẹ́jọ́ àwọn afurasí tí…

Ilé-ẹjọ́ gíga ti ìjọba àpapọ̀, tí a mọ̀ si Federal High Court tó wà nílùú Abuja , ni wọn ti  fàáké kọ́rí láti sègbẹ́jọ́ àwọn afurasí  mẹtala tí wọ́n kó nílé Sunday Igboho ni ọjọ kinni osu keje,  nítorí ọdún iléyá.…

Ilé ìgbìmọ̀ asòfin Nàíjíríà àti Ghana yóò fọwọ́sowọ́pọ̀ lórí ètò òfin ọrọ̀ ajé

ilé ìgbìmọ̀ asojú -sòfin orílẹ̀ èdè Nàíjíríà àti orílẹ̀ èdè  Ghana ti fẹnukò lórí òfin tí ilé ìgbìmọ̀ asojú -sòfin méjéèjì yóò máa lò láti leè tẹpẹlẹ mọ́ ìbásepọ̀ àwọn méjéèjì pàápàá jùlọ…

Ẹ mú ètò ìwòsàn àwọn ọmọ ogun Nàíjíríà ní ọ̀kúnkúndùn-Ahmad Lawan

Abẹnugan ilé ìgbìmọ̀ asòfin lórílẹ̀ èdè Nàíjíríà, Ahmad Lawan  ti rọ àwọn adarí ilé-isẹ́ ọmọ  ogun orílẹ̀ èdè yìí láti mú ètò ìwòsàn àwọn ọmọ ogun  orílẹ̀ èdè yìí ní ọ̀kúnkúndùn, kí wọ́n sì sàtúnse…

Nàíjíríà ń sàjọyọ̀ ayẹyẹ odún ìjọba tiwa-n-tiwa nínú wàhálà òsèlú àti ọrọ̀ ajé…

Abẹnugan ilé ìgbìmọ̀ asòfin lórílẹ̀ èdè Nàíjíríà, Ahmad Lawan ti ní ó seni láàánú pé nínú wàhálà àti ìpèníjà  òsèlú àti ọrọ̀ ajé  ni orílẹ̀ èdè Nàíjíríà ti ń se  ayẹyẹ ọdún ìjọba tiwa-n- tiwa ti…

Ẹ máa sàánú àwọn olè, ajínigbé,ọ̀daràn, ẹ ṣe wọ́n bí ọsẹ se ń sojú-Buhari

Ààrẹ orílẹ̀ èdè Nàíjíríà, Muhammadu Buhari, ti pàsẹ fún gbogbo àwọn ilé-isẹ́ agbófinró àti ilé-isẹ́ ọmọ ogun orílẹ̀ èdè yìí láti máa sàánú àwọn olè, ajínigbé  ọ̀daràn àti àwọn tí wọ́n ń da omi…

Wọ́ ti rí òkú àwọn ènìyàn mẹ́rìndínlọ́gọ́rin tó pàdánù ẹ̀mí wọn nínú ọkọ̀ ojú omi…

Gomina ipinlẹ Kebbi ti ní  wọ́n ti rí òkú àwọn ènìyàn mẹ́rìndínlọ́gọ́rin tó padanu ẹmi wọn ninu ọkọ̀ ojú omi tó dànù ní Kebbi. Atiku Bagudu tun tẹsiwaju pe ijọba oun yoo seto atunse ofin ti yoo fi ilana ti awọn awakọ oju…
button