Nàíjíríà ń sàjọyọ̀ ayẹyẹ odún ìjọba tiwa-n-tiwa nínú wàhálà òsèlú àti ọrọ̀ ajé -Ahmad Lawan
Ademọla Adepọju
Abẹnugan ilé ìgbìmọ̀ asòfin lórílẹ̀ èdè Nàíjíríà, Ahmad Lawan ti ní ó seni láàánú pé nínú wàhálà àti ìpèníjà òsèlú àti ọrọ̀ ajé ni orílẹ̀ èdè Nàíjíríà ti ń se ayẹyẹ ọdún ìjọba tiwa-n- tiwa ti ọdún yìí.
Ninu atẹjade kan ti abẹnugan Ahmad gbe jade pe , “Mo ba gbogbo ọmọ orilẹ ede Naijiria yọ̀ nipa ayẹyẹ ajọdun eto ijọba tiwa-n-tiwa .”
O wa rọ gbogbo ọmọ orilẹ ede Naijiria lati lo ayẹyẹ ajọdun eto ijọba tiwa-n-tiwa ọhun fun idagbasoke eto isọkan ati ifẹ .
O ni atunse eto ofin ti ile igbimọ asofin gunle yii , yoo tun jẹ ki eto ijọba tiwa-n-tiwa tubọ fẹsẹ mulẹ si lorilẹ ede Naijiria.
Leave a Reply