Take a fresh look at your lifestyle.

ìsẹ́ àti àínísẹ́ ló ń fa wàhálà lórí ètò ààbò- Buhari

Ademọla Adepọju

0 119

Ààrẹ orílẹ̀ èdè Nàíjíríà,  Muhammadu Buhari ti ní ìjọba òun ti se gudugudu méje , yàyà mẹ́fa láàrin ọdún mẹ́fà tí wọn ti wà lórí àlèéfà láti ṣe àtúnse tó gbóúnjẹ fẹ́gbẹ́, gbàwo bọ̀ lórí ètò ọrọ̀ ajé.

Aarẹ sọrọ yii lasiko to n ba gbogbo ọmọ orilẹ ede Naijiria sọrọ lori  ẹrọ mohun-maworan , lati ṣe ami ayẹyẹ ajọdun ọdun mejilelogun  eto ijọba tiwa-n-tiwa lorilẹ ede Naijiria

Aarẹ ni ìsẹ́ ati àínísẹ́ lo n fa a ti eto aabo orilẹ ede Naijiria se n wọ́lẹ̀  amosa, ijọba ti n gbe igbesẹ lati fopin ṣi isoro wọnyi.

 

 

Leave A Reply

Your email address will not be published.