Take a fresh look at your lifestyle.

Sunday Igboho:Ilé-ẹjọ́ gíga ti ìjọba àpapọ̀ fàáké kọ́rí láti sègbẹ́jọ́ àwọn afurasí tí wọ́n kó nílé Sunday Igboho nítorí ọdún iléyá

0 187

Ilé-ẹjọ́ gíga ti ìjọba àpapọ̀, tí a mọ̀ si Federal High Court tó wà nílùú Abuja , ni wọn ti  fàáké kọ́rí láti sègbẹ́jọ́ àwọn afurasí  mẹtala tí wọ́n kó nílé Sunday Igboho ni ọjọ kinni osu keje,  nítorí ọdún iléyá.

Eto igbẹjọ ọhun lo yẹ ko waye lonii to jẹ Ogunjọ, osu keje , ọdun ti a wayii sugbon ti o fori sọnpan nitori ọdun ileya. ko si ẹnikankan yala lati ile-isẹ ọtẹlẹmuyẹ , DSS  tabi agbẹjọro fun awọn afurasi ọhun lasiko naa.

 

 

Ademọla Adepọju

 

Leave A Reply

Your email address will not be published.