Browsing Category
ÌRÒYÌN ÈTÒ Ọ̀GBÌN
Ìjọba Ìpínlẹ̀ Ògùn pawọ́pọ̀ Pẹ̀lú ilé ìfowópamọ́ Agbaye Lori ilẹ pinpin
Ìjọba ìpínlẹ̀ Ògùn ti fìdíẹ̀ múlẹ̀ pé òun ń ṣe àjọṣepọ̀ pẹ̀lú ilé-ìfowópamọ́ Àgbáyé láti fún rírì ọrọ̀ ajé lóríi gbígba ilè àti pínpín fún iṣé ọ̀gbìn lókun.
Gomina Ipinlẹ naa, Dapọ Abiọdun, nibi apejọ…
Kòkó: Ìròyìn Ayọ̀! Ẹgbẹ̀rún Lọ́nà Àádọ̀rin-dín-méjì Àgbẹ̀ Yóò Jàǹfààní Ìrànwọ́ Amẹ́ríkà
Ó kéré tán, àgbẹ̀ ní orílè-èdè Nàìjíríà ní ìpínlè Abia, Cross River, Ekiti, Akwa Ibom, Ondo ati Osun ni yóò jẹ ànfààní Ìrànwọ́ orílè-èdè Amẹ́ríkà ní ẹ̀ka ètò ìmúgbóòrò kòkó.
Ẹ̀ka orílè-èdè Amerika tó wà fún Ètò Ogbin fún itẹsiwaju ló sọ…
Ìpínlẹ́ Cross River Tí Pèsè Ibùdó Ẹrọ Ìgbàlódé Fún Kókó
Ìjọba Ipinlẹ Cross River tí pari èéto Ibùdó Ẹrọ ìgbàlódé tí à lè fi Kókó ṣé ní Ikom sì Ilé ìṣẹ AA Universal Agro (AAU).
Gomina Ipinlẹ yìí, Ọjọgbọ́n Ben Ayade, nínú Iwe Ìfìmọ̀ṣọ̀kan tí wọ́n fọwọsi ni Gbọ̀ngàn ilé ìṣẹ rẹ ní…
Àwọn Ẹgbẹ́ Kàn Ṣé Idanilẹkọ Ìṣòwò Adìẹ Ní Ìgbàlóde Fún Àwọn Obìnrin Àti Ọdọ
Ilé-iṣẹ́ Quarantine Agricultural Nigeria (NAQS) tí ṣé idanilẹkọ fún àádọta àwọn olùgbé Ajerọmi/Ajegunle Federal Constituency, ní Ìpínlè Èkó, lórí ìṣòwò adìẹ ní ìgbàlódé.
Idanilẹkọ ọlọjọ marun-un náà ló wáyé ní gbọ̀ngán Bọla Ahmed…
Ìjọba Ìpínlẹ̀ Yóbè Pèsè Ajílẹ̀ lọ́pọ̀ Yanturu
Ìjọba ìpínlẹ̀ Yóbè fi léde ní ọjọ́ Àbámẹ́ta wípé, ó ti ná owó tí ó tó bílíọ̀nù méjì ó lé ọwọ́ mésàn án fún ìpèsè ajílẹ̀ láti ọdún 2019 di àkókò yìí.
Dókítà Mairo Amshi, tí ó jẹ́…
Ọ̀jọ̀gbọ́n Pè Fún Ètò Ìse Ọ̀gbin Alaádàńlá Ti Ètò Ẹ̀rọ Ní Orílè-Èdè Nàìjíríà
Ọ̀jọ̀gbọ́n kan nínú ètò Ìse Ọ̀gbìn alaádàńlá nípa ètò ẹ̀rọ àti Olùdarí Fàdámà NG-CARES ní ìpínlẹ̀ Kwara, Ọ̀gbéni Busari Isiaka ti rọ ìjọba ní gbogbo ẹ̀ka ní orílè-èdè Nàìjíríà láti múra sí iṣẹ́ àgbẹ̀ ti alaádàńlá nípa ètò ẹ̀rọ kí oúnjẹ…
Ìjọba Nàìjíríà Fi Àwọn Ohun Èlò Fún Ilé Ẹ̀kọ́ Ọ̀gbìn Lélẹ̀
Mínísítà Ọgbin Àti Ìdàgbàsókè Ìgbèríko, Dọ́kítà Mohammad Abubakar, tì ṣé ìfilọ́lẹ̀ Ibùgbé àwọn Akẹkọọ àti ile ìṣẹ fún Ilé Ẹ̀kọ́ Ọgbin Àti Ìdàgbàsókè Ìgbèríko (ARMTI) ní Olú ìlú Nàìjíríà ní Abuja. Ezeaja Ikemefuna, Olórí Atotonu (ARMTI) ní…
Ìjọba Nàìjíríà Ṣé ìwé-ẹri Ìwé-àṣẹ Fún Àwọn Oníṣòwò Ajilẹ
Ìjọba Àpapọ̀, ní Ọjọ́bọ̀, ṣé agbekalẹ àwọn iwe-ẹri àti iyọnda títà àti rírà ajilẹ ní ilẹ̀ Nàìjíríà.
Èyí wà nínú ọrọ kàn tí Iyaafin Modupe Olatunji, tí Federal Ministry of Agriculture and Rural development ni Abùjá
Akọ̀wé àgbà,…
FAO bẹnu àtẹ́ lu bí aginju ̀ṣe ń parun
Àjọ iṣọkan tó ń mójú tó ètò oúnjẹ àti iṣẹ́ àgbẹ̀ lagbaye (FAO), ti tako bí wọ́n ṣe n pàdánù aginjù látàrí pípa igbó run.
Gẹgẹ bi FAO ti ṣalaye, awọn aginju agbaye wa lọwọ ewu,nitori pe o ti le- nirinwo miliọnu eeka aginju to ti…
Gómìnà Ìpínlẹ̀ Èkó Se Ìlérí Láti Kojú Àwọn Ìpèníjà Tí Àwọn Onìpinlẹ̀ṣẹ̀ Ń…
Gómìnà ìpínlẹ̀ Ìlú Èkó, Ọ̀gbẹ́ni Babájídé Sanwó-Olú, ti ṣe ìlérí láti kọjú àwọn ìpèníjà tí àwọn Onìpinlẹ̀ṣẹ̀ ètò iṣẹ-ọ̀gbìn ń dojú kọ lórílẹ̀, ó tún sèlérí fífún àwọn ènìyàn ní ìrètí nípasẹ̀…